Dataset Viewer
Auto-converted to Parquet
score
float32
1.04
1.25
Shona
stringlengths
9
500
Yoruba
stringlengths
1
501
1.24949
Zvino wakati ari oga, vakanga vakamukomba navanegumi navaviri vakamubvunza zvemufananidzo.
10 Nigbati o kù on nikan, awọn ti o wà lọdọ rẹ̀ pẹlu awọn mejila bi i lẽre idi owe na.
1.248534
Vanotaura mutauro mumwechete!
Wọn sọ èdè kan naa!
1.248477
Ko, zvakadai zvakatomboitika here pamazuva enyu, kana pamazuva amadzitateguru enyu?
Ǹjẹ́ irú ìṣẹ̀lẹ̀ yìí ti ṣẹlẹ̀ rí ní àkókò yín,tabi ní àkókò àwọn baba yín?
1.24842
Vashumiri vangu vachafara, asi imi muchanyara.
Àwọn iranṣẹ mi yóo máa yọ̀,ṣugbọn ìtìjú yóo máa ba yín.
1.248167
navakatendeukira kuchiJudha); vaKirete navaArabhu, tinovanzwa vachitaura zvishamiso zvaMwari
àwọn Juu ati àwọn aláwọ̀ṣe ẹ̀sìn Juu; àwọn ará Kirete ati àwọn ará Arabia, gbogbo wa ni a gbọ́ tí wọ́n ń sọ àwọn iṣẹ́ ńlá Ọlọrun ní oríṣìíríṣìí èdè wa.
1.247664
vachazvidavirira kuna iye akazvigadzirira kutonga vapenyu navakafa.
Ṣugbọn wọn óo dáhùn fún ìwà wọn níwájú ẹni tí ó ṣetán láti ṣe ìdájọ́ alààyè ati òkú.
1.247596
Nokuti dai Joshua akanga avapa zororo, Mwari angadai asina kuzotaurazve nezverimwe zuva.
Bí ó bá jẹ́ pé Joṣua fún wọn ní ìsinmi ni, Ọlọrun kò ní tún sọ nípa ọjọ́ mìíràn mọ́ lẹ́yìn ọjọ́ pupọ.
1.247583
Kunyange zvakadaro hazvo, musafara nokuti mweya yakaipa inozviisa pasi penyu, asi farai kuti mazita enyu akanyorwa kudenga."
Ẹ má yọ̀ ní ti pé àwọn ẹ̀mí èṣù gbọ́ràn si yín lẹ́nu; ṣugbọn ẹ máa yọ̀ nítorí a ti kọ orúkọ yín sí ọ̀run.
1.247056
asi saiye mutsvene wakakudanai, nemivo mumene muve vatsvene pamufambire wenyu wose;
Ṣugbọn gẹ́gẹ́ bí ẹni tí ó pè yín ti jẹ́ mímọ́, bẹ́ẹ̀ ni kí ẹ̀yin náà jẹ́ mímọ́ ninu gbogbo ìwà yín.
1.246996
Vakanyengetera kuna Mwari, kwete kuna Jesu.
Ọlọ́run ni wọ́n gbàdúrà sí, kì í ṣe Jésù.
1.246937
Munhu anofamba haakwanisi kudzora nhanho dzake."
Kì í ṣe ti ènìyàn tí ń rìn àní láti darí àwọn ìṣísẹ̀ ara rẹ̀."
1.246329
zvisati zviri izvo bedzi, asi tinofara zvikuruvo munaMwari naShe wedu Jesu Kristu, watakapiwa zvino naye iko kuyananiswa.
Kì í ṣe bẹ́ẹ̀ nìkan, ṣugbọn à ń yọ̀ ninu Ọlọrun nítorí ohun tí ó ṣe nípa Oluwa wa Jesu Kristi, ẹni tí ó sọ wá di ọ̀rẹ́ Ọlọrun ní àkókò yìí.
1.246006
Uye vangaparidza seiko kana vasina kutumwa?
Báwo ni àwọn kan yóo ṣe lọ kéde rẹ̀ láìjẹ́ pé a bá rán wọn lọ?
1.245215
Ndicharipa mhiko dzangu ndiri pamberi pevaya vanomutya.
ẹ̀jẹ́ rẹ̀ ni èmi yóò san níwájú àwọn tí o bẹ̀rù rẹ̀
1.24484
VaSadhusi vanoti hakuna kumuka kwavakafa, uye kuti hakuna mutumwa kana mweya, asi vaFarisi vanotenda izvozvo zvose.
Nítorí àwọn Sadusi sọ pé kò sí ajinde, bẹ́ẹ̀ ni kò sí angẹli tabi àwọn ẹ̀mí; ṣugbọn àwọn Farisi gbà pé mẹtẹẹta wà.
1.244677
Kare, Mwari akataura kumadzitateguru edu kubudikidza navaprofita panguva zhinji, uye nenzira dzakasiyana-siyana,
Ní ìgbà àtijọ́, oríṣìíríṣìí ọ̀nà ni Ọlọrun fi ń bá àwọn baba wa sọ̀rọ̀ láti ẹnu àwọn wolii rẹ̀.
1.244331
Kufurirwa ikoko hakusi kwaiye akakudaidzai.
Ìyípadà ọkàn yín kì í ṣe láti ọ̀dọ̀ Ọlọrun tí ó pè yín.
1.242797
kuti kurege kuva nenyama ingazvikudza pamberi paMwari.
Ìdí tí Ọlọrun fi ṣe báyìí ni pé kí ẹnikẹ́ni má baà lè gbéraga níwájú òun.
1.242791
Semiseve mumaoko emhare ndizvo zvakaita vanakomana voujaya.
Bí ọfà ti rí ní ọwọ́ alágbára, bẹ́ẹ̀ ni àwọn ọmọ èwe.
1.242443
Ndezvipi 20 chokwadi pamusoro pangu?
Kini awọn otitọ 20 nipa mi?
1.241713
Ivo vakavimba nesu, pakati pevamwe:
Wọn gbẹkẹle wa, laarin awọn miiran:
1.240933
Nekuti ani nani unoita kuda kwaBaba vangu vari kumatenga, ndiye hama yangu, nehanzvadzi, namai.
Nítorí ẹnikẹ́ni tí ó bá ṣe ìfẹ́ Baba mi tí ń bẹ ní ọ̀run, òun ni arakunrin mi ati arabinrin mi ati ìyá mi.
1.240722
Ndiri kuda kujoina John nechimwe chikonzero.
Mo fẹrẹ darapọ mọ John fun idi miiran.
1.240032
Asi shoko raMwari rakaramba richikura uye richipararira.
Ọ̀rọ̀ Ọlọrun bẹ̀rẹ̀ sí fìdí múlẹ̀ sí i, ó sì túbọ̀ ń tàn káàkiri.
1.239723
kuti zvakataurwa navaprofita zvirege kuitika kwamuri, zvinoti:
Nítorí náà, ẹ ṣọ́ra kí ohun tí a kọ sílẹ̀ ninu ìwé àwọn wolii má baà dé ba yín:
1.239455
Neni ndinoti kwamuri: Muzviitire shamwari nafuma wekusakarurama, kuti kana musingachagoni, vakugamuchirei mudzimba dzekusingaperi. (aiōnios g166)
"Ní tèmi, mò ń sọ fun yín, fún anfaani ara yín, ẹ fi ọrọ̀ ayé yìí wá ọ̀rẹ́ fún ara yín, tí ó fi jẹ́ pé nígbà tí owó kò bá sí mọ́, kí wọn lè gbà yín sí inú ibùgbé tí yóo wà títí lae.
1.239401
Asi nokutenda tinoshinga kwazvo kumirira kururama, kunova ndiko kwatine tariro nako kubudikidza noMweya.
Ṣugbọn ní tiwa, nípasẹ̀ Ẹ̀mí ni à ń retí ìdáláre nípa igbagbọ.
1.23938
Vashumiri vangu vachafara, asi imi muchanyara."
Àwọn iranṣẹ mi yóo máa yọ̀,ṣugbọn ìtìjú yóo máa ba yín.
1.239247
29 Zvino akavataurira mufananidzo achiti*: Tarirai muvonde nemiti yose;
Ó pa òwe kan fún wọn, ó ní, "Ẹ wo igi ọ̀pọ̀tọ́ ati gbogbo igi yòókù.
1.239236
Wakadya kanhi muti wandakakuraira kuti urege kuu dya?"
Àbí o ti jẹ ninu èso igi tí mo pàṣẹ fún ọ pé o kò gbọdọ̀ jẹ?"
1.239028
Vakanga vamire padyo naye vakati, "Unoda kushora mupristi mukuru waMwari here?"
Àwọn tí wọ́n dúró níbẹ̀ bá ní, "Olórí Alufaa Ọlọrun ni ò ń bú bẹ́ẹ̀?
1.238604
Nokuti zvinhu izvi zvakaitwa kuti rugwaro ruzadzisike runoti: Fupa rake haringavhunwi.
Gbogbo èyí rí bẹ́ẹ̀ kí Ìwé Mímọ́ lè ṣẹ tí ó wí pé, "Kò sí egungun rẹ̀ kan tí wọ́n ṣẹ́.
1.238477
5 hatina kuvatsedukira ivava, tichivateerera nguva imwe; kuti chokwadi cheevhangeri chirambe ichigara nemi.
Ṣugbọn a kò fi ìgbà kankan gbà wọ́n láyè rárá, kí ó má dàbí ẹni pé ọ̀rọ̀ tiwọn ni ó borí, kí òtítọ́ ìyìn rere lè wà pẹlu yín.
1.238448
"Ipapo vaya varere muna Kristu vaparara.
→ Awon ti o ti ku ninu Kristi yoo wa jade ti won ibojì ni ipè.
1.237216
uye vabaire chibairo sezvazvakarehwa pamurairo waIshe, njiva mbiri, kana vana vaviri vehangaiwa.
Wọ́n tún lọ láti rú ẹbọ gẹ́gẹ́ bí ó ṣe wà ninu òfin Oluwa: pẹlu àdàbà meji, tabi ọmọ ẹyẹlé meji.
1.236448
uye kumirira kwamunoita Mwanakomana wake kubva kudenga iye waakamutsa kuvakafa, Jesu anotinunura kuhasha dzaMwari dziri kuuya.
ati bí ẹ ti ń retí Jesu, Ọmọ rẹ̀, láti ọ̀run wá, ẹni tí a jí dìde ninu òkú, tí ó yọ wá kúrò ninu ibinu tí ń bọ̀.
1.236203
pake, achatsaura vanhu mumwe kubva kuno mumwe somufudzi anotsaura makwai kubva
On o si yà wọn lati ọkan miiran, gẹgẹ bi oluṣọ ya awọn agutan lati ewúrẹ.
1.236171
Rambai muchiita izvi muchindiyeuka.'
Ẹ máa ṣe èyí ní ìrántí mi.
1.236157
akasamuziʋa kuȿikira aɀara mŋanakomana wake weɗaŋgwe, ndokumutumidza zita rinonzi Jesu.
Ṣùgbọ́n òun kò mọ̀ ọ́n títítí ó fi bí ọmọkùnrin, òun sì sọ orúkọ rẹ̀ ní Jésù.
1.235273
Nemimwe mifananidzo yakadai, Jesu akataura shoko kwavari, zvose zvavaigona kunzwisisa.
Pẹlu ọpọlọpọ irú òwe bẹ́ẹ̀ ni Jesu fi ń sọ̀rọ̀ ìyìn rere fún wọn, gẹ́gẹ́ bí òye wọn ti mọ láti lè gbọ́.
1.235256
Kufanana nevaapostora, tinoparidza paimba neimba.
Bíi ti àwọn àpọ́sítélì, a máa ń wàásù láti ilé dé ilé.
1.234745
Uyo zvake anoda mari haazombowani mari yakakwana; ani zvake anoda pfuma haazombogutswi nezvaanowana.
Kò sí iye tó lè tẹ́ ẹni tí ó bá ní ìfẹ́ owó lọ́rùn; bákan náà ni ẹni tí ó bá fẹ́ràn ọrọ̀, kò sí iye tí ó lè jẹ lérè tí yóo tẹ́ ẹ lọ́rùn.
1.234696
Imi makachena, kunyange zvazvo musiri mose vakachena."
Ẹ̀yin mọ́, ṣugbọn kì í ṣe gbogbo yín."
1.234416
(We akati, chii chichaitika kune 630,000?
(A si wipe, ohun ti yoo ṣẹlẹ si awọn 630.000?
1.234084
Nokukumbira kwaJoseph Knight, Muporofita akabvunza kuna Ishe uye akagashira zvakazarurwa izvi.
Nítorí ẹ̀bẹ̀ Joseph Knight, Wolíì náà béèrè lọ́wọ́ Olúwa ó sì gba ìfihàn.
1.233974
Nokuti dai Joshuwa akanga avapa zororo, Mwari angadai asina kuzotaura pashure nezverimwe zuvazve.
Bí ó bá jẹ́ pé Joṣua fún wọn ní ìsinmi ni, Ọlọrun kò ní tún sọ nípa ọjọ́ mìíràn mọ́ lẹ́yìn ọjọ́ pupọ.
1.233521
Asi kana pasina kumuka kwevakafa, ipapo kunyange Kristu akamutswa.
Bí kò bá sí ajinde òkú, a jẹ́ pé a kò jí Kristi dìde.
1.233155
15:11 Nokuti kana ini kana ivo: saka isu tinoparidza, uye saka makatenda.
Nítorí náà, ìbáà ṣe èmi ni, tabi àwọn aposteli yòókù, bákan náà ni iwaasu wa, bẹ́ẹ̀ sì ni ohun tí ẹ gbàgbọ́.
1.232399
Johani 16 1 "Ndakuudzai zvose izvi kuitira kuti murege kutsauka.
"Mo sọ gbogbo nǹkan yìí fun yín kí igbagbọ yín má baà yẹ̀.
1.231731
3:11 Zvino, zvinovonekwa kuti hakunamunhu unoruramiswa nomurairo pamberi paMwari, nokuti: Wakarurama uchararama nokutenda.
Ó dájú pé kò sí ẹnikẹ́ni tí Ọlọrun yóo dá láre nípa òfin, nítorí a kà á pé, "Olódodo yóo wà láàyè nípa igbagbọ.
1.231683
Pinda mumufaro watenzi wako!'
Wọ inu didùn ti oluwa rẹ. '
1.231323
Israeli akanatsatira njira zanga,
bí Israẹli yóò bá tẹ̀lé ọ̀nà mi,
1.231202
14 Masikirwo akaitwa vanhu haakudzidzisii here kuti kana murume aine bvudzi refu, zvinoita kuti azvidzwe;
Mo ṣebí ìṣe ẹ̀dá pàápàá kọ yín pé tí ọkunrin bá jẹ́ kí irun rẹ̀ gùn, ó fi àbùkù kan ara rẹ̀;
1.231095
14 "Unganai imi mose, munzwe; ndianiko pakati pavo akaparidza zvinhu izvi?
14 Gbogbo nyin, ẹ pejọ, ẹ si gbọ́; tani ninu wọn ti o ti sọ nkan wọnyi?
1.231035
chifukwa ine ndidzachita china chake mʼmasiku anu,
Nítorí èmi ó ṣe ohun kan ní ọjọ́ yín
1.230908
zwinoshamisa ku meso edu ?"
ó sì jẹ́ ìyanu ní ojú wa'?
1.230821
Uye vakagara pasi, vakamurindapo.
Wọ́n bá jókòó níbẹ̀, wọ́n ń ṣọ́ ọ.
1.230704
"Zvauri guruva, uchadzokerazve kuguruva"
"Ìwọ ó sì padà di erùpẹ̀"
1.230076
Uye kana wanga usina kutendeka ipi zvomumwe, ndianiko achakupa zvinhu zvako iwe?
Bí ẹ kò bá ṣe é gbẹ́kẹ̀lé nípa ohun tí ó jẹ́ ti ẹlòmíràn, ta ni yóo fun yín ní ohun tí ó jẹ́ ti ẹ̀yin fúnra yín?
1.229541
Kuti vakutye mazuva ese avanogara munyika yamakapa madzibaba edu.
kí wọ́n lè máa bẹ̀rù rẹ ní gbogbo ọjọ́ tí wọ́n óo gbé lórí ilẹ̀ tí o fi fún àwọn baba ńlá wọn.
1.229526
23 Asi mumwe nomumwe padzoro rake: Kristu chibereko chokutanga; ipapo paanouya,
23 Ṣugbọn olukuluku enia ni ipa tirẹ̀: Kristi akọbi; lẹhin eyini awọn ti iṣe ti Kristi ni bibọ rẹ̀.
1.22914
24 Kuna iye anogona kukuchengetai kuti murege kugumburwa uye anokuisai pamberi pokubwinya kwake musina chamunopomerwa, uye nomufaro mukuru,
Njẹ ti ẹniti o le pa nyin mọ́ kuro ninu ikọsẹ, ti o si le mu nyin wá siwaju ogo rẹ̀ lailabuku pẹlu ayọ nla, 25.
1.228967
Ko, zvakadai zvakatomboitika here pamazuva enyu, kana pamazuva amadzitateguru enyu?
Eyi ha wà li ọjọ nyin, tabi li ọjọ awọn baba nyin?
1.228772
Paunonzwa ivo vachitaura, sekunge ivo vane 'huchenjeri' hwese mumaoko avo.
Nigbati o gbọ ti wọn sọrọ, bi ẹni pe wọn ni gbogbo 'ọgbọn' ni ọwọ wọn.
1.228641
12 Zvino ichi ndicho chiratidzo kwamuri: muchawana mucheche akaputirwa nemachira, akarara muchidyiro chezvipfuwo."
2:12 Eyi yoo si jẹ ami fun ọ: ẹnyin o ri ọmọ-ọwọ ti a fi aṣọ wé, ti o dubulẹ si ibujẹ ẹran.
1.228261
Nokuti isu tiri munhuwi wakanaka waKristu kuna Mwari pakati paavo vari kuponeswa navari kuparara.
Nítorí àwa ni òórùn dídùn tí Kristi fi rúbọ sí Ọlọrun lọ́dọ̀ àwọn tí à ń gbàlà ati àwọn tí ń ṣègbé.
1.228223
"Makavararamisa makore makumi mana murenje, vakasashaiwa chinhu; nguvo dzavo hadzina kusakara, uye tsoka dzavo hadzina kuzvimba.
Ogoji ọdún ni o fi bọ́ wọn ninu aṣálẹ̀, wọn kò sì ṣe àìní ohunkohun, aṣọ wọn kò gbó, ẹsẹ̀ wọn kò sì wú.
1.228106
Ndichagara ndichikuda, Emerson! "
Mo fẹràn rẹ nigbagbogbo, Emerson! "
1.22785
saizvozvowo Kristu akabayirwa kamwe chete kuti atakure zvivi zvavanhu vazhinji; uye achazoonekwa kechipiri, asingatakuri zvivi, asi kuti auyise ruponeso kuna avo vakamumirira.
Bákan náà ni Kristi, nígbà tí a ti fi rúbọ lẹ́ẹ̀kan láti kó ẹ̀ṣẹ̀ ọpọlọpọ lọ, yóo tún pada lẹẹkeji, kì í ṣe láti tún ru ẹ̀ṣẹ̀ mọ́, ṣugbọn láti gba àwọn tí ó ń fi ìtara retí rẹ̀ là.
1.227717
Ndakamirira kwenguva yakareba kamera iyi.
Mo duro de igba pipẹ fun kamera yii.
1.227712
Hakuna unonzwisisa.Hakuna unotsvaka Mwari;
Kò sí ẹni tí òye yé, kò sí ẹni tí ó ń wá Ọlọrun.
1.227391
Akawedzera kuti: "Ndinogara ndichiita zvinhu zvinomufadza."
Ó tún sọ pé: "[Ìgbà] gbogbo ni mo ń ṣe ohun tí ó wù ú."
1.227356
Nokuti mumwe waava anofanira kuva chapupu chokumuka kwake, pamwe chete nesu."
Ó yẹ kí ọ̀kan nínú àwọn wọ̀nyí ṣe ẹlẹ́rìí àjíǹde rẹ̀ pẹ̀lú wa."
1.226896
asi kunavakadamwa, vaJudha navaGiriki Kristu isimba raMwari novuchenjeri hwaMwari.
ṣugbọn lójú àwọn tí Ọlọrun pè, ìbáà ṣe Juu tabi Giriki, Kristi yìí ni agbára Ọlọrun, òun ni ọgbọ́n Ọlọrun.
1.226839
Iyesu ndisu kunhuwirira kwaKristu kuna Mwari pakati pavari kuponeswa napakati pavari kuparadzwa.
Nítorí àwa ni òórùn dídùn tí Kristi fi rúbọ sí Ọlọrun lọ́dọ̀ àwọn tí à ń gbàlà ati àwọn tí ń ṣègbé.
1.226664
Asi tinoda inzwi rako zvino.
Sugbon a nilo ohùn rẹ bayi.
1.226594
Asi zvirokwazvo naMwari akatendeka, shoko redu kwamuri harizi "Hongu" kana "Kwete."
Gẹ́gẹ́ bí Ọlọrun ti ṣe é gbẹ́kẹ̀lé, ọ̀rọ̀ wa pẹlu yín ti kúrò ní "bẹ́ẹ̀ ni" ati "bẹ́ẹ̀ kọ́.
1.226012
Zvose zvinoenda kuzvimbo imwe chete; zvose zvinobva kuvhu zvose zvinodzokera.
Ibìkan náà ni gbogbo wọn ń lọ; inú erùpẹ̀ ni gbogbo wọn ti wá, inú erùpẹ̀ ni wọn yóo sì pada sí.
1.225906
Chitendero chechokwadi chiri kubatanidza vanhu
Ẹ̀sìn tòótọ́ ń mú kí àwọn èèyàn wà níṣọ̀kan
1.225504
'Munhu anopa kuonga sechibayiro chake anokudza Mwari.' - Pisarema 50:23.
"Ẹni tí ń rú ìdúpẹ́ gẹ́gẹ́ bí ẹbọ rẹ̀ ni ó ń yìn [Ọlọ́run] lógo." - Sáàmù 50:23.
1.225055
Mwedzi wako wekutanga wave patiri!
Oṣu akọkọ rẹ wa lori wa!
1.224581
70 sezvaakataura nomuromo wavaporofita vake vatsvene, vakanga varipo kubva pakuvamba kwenyika,
gẹ́gẹ́ bí ó ti sọ láti ẹnu àwọn wolii rẹ̀ mímọ́,láti ọjọ́ pípẹ́;
1.224373
Mumwe nomumwe unoita zvivi unodarika nomurairowo; zvivi ndiko kudarika murairo.
Gbogbo ẹni tí ó bá ń dẹ́ṣẹ̀ ń rú òfin, nítorí rírú òfin ni ẹ̀ṣẹ̀.
1.224218
Mwari aida kuti tife here?
Ṣé ìfẹ́ Ọlọ́run ni pé kí àwa èèyàn máa kú?
1.224057
'Kana vasinganzwi Mozisi navaprofita. . .
'Ti o ba won ko ba ko gbọ ti Mose ati ti awọn woli. . .
1.224017
Zvino tarirai, mukuru kunaSoromoni pano.
Si kiyesi i, diẹ ẹ sii ju Solomoni jẹ nibi.
1.224011
WHSR akaita izvi kwauri.
WHSR ti ṣe eyi fun ọ.
1.223861
Nekuti handina kusiya kutaura kwamuri simba raMwari.
Nítorí n kò dánu dúró láti sọ gbogbo ohun tí Ọlọrun fẹ́ fun yín.
1.223732
Meso ose anotarisa kwamuri imi muchivapa chokudya chavo nenguva yakafanira.
Ojú gbogbo eniyan ń wò ọ́,o sì fún wọn ní oúnjẹ wọn ní àsìkò.
1.222981
Uye kana Kristu asina kumutswa, kutenda kwako hazvina maturo uye muchiri muzvivi zvenyu.
Bí a kò bá sì jí Kristi dìde, a jẹ́ pé lásán ni igbagbọ yín, ẹ sì wà ninu ẹ̀ṣẹ̀ yín sibẹ.
1.222925
Mwari akanga atigadzirira chimwe chinhu chiri nani pakunaka, kuitira kuti ivo pamwe chete nesu tigozokwaniswa.
Nítorí pé àwa ni Ọlọrun ní lọ́kàn tí ó fi ṣe ètò tí ó dára jùlọ, pé kí àwa ati àwọn lè jọ rí ẹ̀kún ibukun gbà.
1.222854
9 Zvisinei, kana kuri kudanana sehama,+ hatifaniri hedu kuti tikunyorerei, nokuti imi munodzidziswa naMwari+ kuti mudanane;+
9 Ṣugbọn niti ifẹ awọn ará, ẹ kò tun fẹ ki ẹnikẹni kọwe si nyin: nitori a ti kọ́ ẹnyin tikaranyin lati ọdọ Ọlọrun wá lati mã fẹ ara nyin.
1.222832
(Pisarema 55:22) Ndizvo zvandiri kuedza kuita mazuva ose.
(Sáàmù 55:22) Ohun tí mo máa ń gbìyànjú láti ṣe lójoojúmọ́ nìyẹn.
1.222804
12 Nokuti mukadzi sezvaakabva pamurume, saizvozvowo murume anozvarwa nomukadzi asi zvose zvinobva kuna Mwari.
12 Nitori gẹgẹ bi obinrin ti ti ara ọkunrin wá, bẹ̃li ọkunrin tipasẹ obinrin wá pẹlu: ṣugbọn lati ọdọ Ọlọrun li ohun gbogbo ti wá.
1.222708
6:22 Naizvozvo Noa akaita zvose sezvakanga Mwari akamurayira.
6:22 Noa si ṣe ohun gbogbo gẹgẹ bi Ọlọrun ti fun u li aṣẹ.
1.222587
Ini, Pauro, ndanyora izvi noruoko rwangu.
Èmi Paulu ni mò ń fi ọwọ́ ara mi pàápàá kọ ìwé yìí.
1.222385
16:15 Rangarirai nokusingaperi sungano yake, shoko akarayira kusvikira kumarudzi ane chiuru,
Títí lae ni ó ń ranti majẹmu rẹ̀,ó ranti àṣẹ tí ó pa fún ẹgbẹẹgbẹrun ìran,
1.222214
London chaizvoizvo ane zvose!
London gan ni o ni gbogbo awọn ti o!
1.2222
Ini ndini chingwa chipenyu chakaburuka kubva kudenga.
Èmi ni oúnjẹ tí ó wà láàyè tí ó ti ọ̀run sọ̀kalẹ̀.
1.221829
PaAugust 28, tichadzidza zvimwe pamusoro pazvo!
Ni Oṣu Kẹjọ Ọjọ 28, a yoo ni imọ diẹ sii nipa rẹ!
End of preview. Expand in Data Studio

Shona-Yoruba_Sentence-Pairs Dataset

This dataset contains sentence pairs for African languages along with similarity scores. It can be used for machine translation, sentence alignment, or other natural language processing tasks.

This dataset is based on the NLLBv1 dataset, published on OPUS under an open-source initiative led by META. You can find more information here: OPUS - NLLB-v1

Metadata

  • File Name: Shona-Yoruba_Sentence-Pairs
  • Number of Rows: 541537
  • Number of Columns: 3
  • Columns: score, Shona, Yoruba

Dataset Description

The dataset contains sentence pairs in African languages with an associated similarity score. Each row consists of three columns:

  1. score: The similarity score between the two sentences (range from 0 to 1).
  2. Shona: The first sentence in the pair (language 1).
  3. Yoruba: The second sentence in the pair (language 2).

This dataset is intended for use in training and evaluating machine learning models for tasks like translation, sentence similarity, and cross-lingual transfer learning.

References

Below are papers related to how the data was collected and used in various multilingual and cross-lingual applications:

[1] Holger Schwenk and Matthijs Douze, Learning Joint Multilingual Sentence Representations with Neural Machine Translation, ACL workshop on Representation Learning for NLP, 2017

[2] Holger Schwenk and Xian Li, A Corpus for Multilingual Document Classification in Eight Languages, LREC, pages 3548-3551, 2018.

[3] Holger Schwenk, Filtering and Mining Parallel Data in a Joint Multilingual Space ACL, July 2018

[4] Alexis Conneau, Guillaume Lample, Ruty Rinott, Adina Williams, Samuel R. Bowman, Holger Schwenk and Veselin Stoyanov, XNLI: Cross-lingual Sentence Understanding through Inference, EMNLP, 2018.

[5] Mikel Artetxe and Holger Schwenk, Margin-based Parallel Corpus Mining with Multilingual Sentence Embeddings arXiv, Nov 3 2018.

[6] Mikel Artetxe and Holger Schwenk, Massively Multilingual Sentence Embeddings for Zero-Shot Cross-Lingual Transfer and Beyond arXiv, Dec 26 2018.

[7] Holger Schwenk, Vishrav Chaudhary, Shuo Sun, Hongyu Gong and Paco Guzman, WikiMatrix: Mining 135M Parallel Sentences in 1620 Language Pairs from Wikipedia arXiv, July 11 2019.

[8] Holger Schwenk, Guillaume Wenzek, Sergey Edunov, Edouard Grave and Armand Joulin CCMatrix: Mining Billions of High-Quality Parallel Sentences on the WEB

[9] Paul-Ambroise Duquenne, Hongyu Gong, Holger Schwenk, Multimodal and Multilingual Embeddings for Large-Scale Speech Mining, NeurIPS 2021, pages 15748-15761.

[10] Kevin Heffernan, Onur Celebi, and Holger Schwenk, Bitext Mining Using Distilled Sentence Representations for Low-Resource Languages

Downloads last month
14

Collection including michsethowusu/shona-yoruba_sentence-pairs