score
float32 1.04
1.25
| Kinyarwanda
stringlengths 10
500
| Yoruba
stringlengths 9
496
|
|---|---|---|
1.249596
|
Ese mu nzu ya so twabonayo icumbi?"
|
Jọ̀wọ́ wí fún mi, ǹjẹ́ ààyè wà ní ilé baba rẹ láti wọ̀ sí ní alẹ́ yìí?"
|
1.249292
|
Ibyanditswe biravuga biti: "Abicisha bugufi azabayobora mu byo gukiranuka, abicisha bugufi azabigisha inzira ze."
|
ó sì kọ́ àwọn onírẹ̀lẹ̀ ní ọ̀nà rẹ̀.
|
1.246066
|
Mbese none roho yaba yaravuganye na we, cyangwa se umumalayika ?"
|
Kini ti ẹmi ba ti ba a sọrọ, tabi angeli?"
|
1.243127
|
Ba bamarayika bombi bagera i Sodomu nimugoroba, Loti yari yicaye mu marembo y'i Sodomu.
|
Ní ìrọ̀lẹ́ ọjọ́ náà ni àwọn angẹli meji náà dé ìlú Sodomu, Lọti sì jókòó ní ẹnubodè ìlú náà.
|
1.243012
|
17Sebukwe wa Musa aramusubiza ati "Uko ugenza uko, nta bwo ari byiza!
|
17 Ana Mose si wi fun u pe, Eyiti iwọ nṣe nì kò dara.
|
1.239601
|
Ba Farawo na Aad na Thamud bamwe
|
85:18 ti Farao, ati ti Thamood ?
|
1.238274
|
Ni cyo cyateye ababyeyi be kuvuga bati "Arakuze, nimumwibarize."
|
Nítorí èyí ni àwọn òbí ọkunrin náà ṣe sọ pé, "Kì í ṣe ọmọde, ẹ bi òun alára léèrè.
|
1.236019
|
19Ni nde mpumyi, uretse umugaragu wanjye ?
|
19Ta ló fọ́jú bí kò ṣe ìránṣẹ́ mi,
|
1.233907
|
Nuko Umwana nababātūra, muzaba mubātūwe by'ukuri.
|
Nítorí náà, bí Ọmọ bá sọ yín di òmìnira, ẹ óo di òmìnira nítòótọ́.
|
1.233639
|
Wacunguje ubwoko bwawe ukuboko kwawe, Ni bwo bene Yakobo na Yosefu.
|
O ti fi agbára rẹ gba àwọn eniyan rẹ là;àní, àwọn ọmọ Jakọbu ati Josẹfu.
|
1.232677
|
28 kuko aya ari amaraso yanjye y'isezerano rishya, ava ku bwa benshi ngo bababarirwe ibyaha
|
28Nítorí èyí ni ẹ̀jẹ̀ mi tí májẹ̀mú tuntun, tí a ta sílẹ̀ fún ìdáríjì ẹ̀ṣẹ̀ ọ̀pọ̀ ènìyàn.
|
1.229397
|
Mwa bantu mwe !
|
Iwọ eniyan!
|
1.228753
|
(Allâh Umugenga wawe Arema uwoashatse n'ibyo Ashaka, akanatoranya [guha inshingano z'ubuyobozi] uwo ashatsecyangwa icyo ashatse.
|
Ðàññ÷èòàåì äëèíó ñêàòåðòè: Äëèíà ñêàòåðòè = 4ì+0,5ì= 4,5 ì Äëèíà ñòîëà - 4 ì, øèðèíà - 4 ì Þáêà = (4,5ì+2*4,5ì) *2=27 ì
|
1.225397
|
Aratonganya imigi yabonye ibitangaza bye byinshi ikarenga ntiyihane.
|
Nígbà náà ni Jesu bẹ̀rẹ̀ sí bá àwọn ìlú wọ̀n-ọn-nì wí níbi tí ó ti ṣe àwọn iṣẹ́ ìyanu pupọ jùlọ, nítorí wọn kò ronupiwada.
|
1.22503
|
(trg) ="3"> Kuyandika biri mu bigize umurimo wo kwigisha Bibiliya ku isi hose , kandi ushyigikiwe n'impano zitangwa ku bushake .
|
(trg) ="3"> Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn .
|
1.224339
|
Uyu munsi muri abagabo bo kubihamya."
|
Ẹ̀yin ni ẹlẹ́rìí ní òní."
|
1.223275
|
Nanga iteraniro ry'inkozi z'ibibi, kandi sinzicarana n'abanyabyaha" (Zaburi 26:4, 5).
|
5 Emi ti korira ijọ awọn oluṣe-buburu; emi kì yio si ba awọn enia buburu joko.
|
1.223256
|
Ariko muragowe mwe bakungu, kuko mwashyikiriye imaragahinda yanyu.
|
"Ṣugbọn ẹ̀yin ọlọ́rọ̀ gbé,nítorí ẹ ti jẹ ìgbádùn tiyín tán!
|
1.220954
|
Akibuka ko turi umukungugu.
|
ó rántí pé erùpẹ̀ ni wá.
|
1.220176
|
"Dore umugaragu wanjye azasagamba, azakuzwa, yererezwe asumbe byose.
|
Iranṣẹ mi yóo ṣe àṣeyọría óo gbé e ga, a óo gbé e lékè;yóo sì di ẹni gíga,
|
1.219393
|
"Mumpamagarira iki muti 'Databuja, Databuja', nyamara NTIMUKORE ibyo mvuga?"
|
"Kí ló dé tí ẹ̀ ń pè mí ní, 'Oluwa, Oluwa,' tí ẹ kì í ṣe ohun tí mo sọ?
|
1.218443
|
Abo bazacirwa uurubanza rukaze kurusha abandi."
|
Wọnyi ni yio si gba awọn siwaju sii sanlalu idajọ. "
|
1.217733
|
Mwa rubyaro rwa Yakobo mwese mwe, nimumuheshe icyubahiro!+
|
Gbogbo ẹ̀yin ìran Jakọbu, ẹ fi ògo fún un!
|
1.217648
|
Jye mvuga ibyo nabonye kwa Data, namwe mukora ibyo mwumvanye so."
|
Ohun tí èmi ti rí lọ́dọ̀ Baba mi ni mò ń sọ, ohun tí ẹ̀yin ti gbọ́ lọ́dọ̀ baba yín ni ẹ̀ ń ṣe.
|
1.216883
|
Igihe cyose mukinywereyeho mujye mukora mutya kugira ngo munyibuke."
|
Nígbàkúùgbà tí ẹ bá ń mu ún, ẹ máa ṣe èyí ní ìrántí mi.
|
1.216852
|
(Mbese utazi gutegeka abo mu rugo rwe yabasha ate kurinda Itorero ry'Imana?)
|
Nítorí ẹni tí kò káwọ́ ilé ara rẹ̀, báwo ni ó ṣe lè mójútó ìjọ Ọlọrun?
|
1.216153
|
abagaragu be guhamagara abatumiwe mu bukwe, ariko banga kuza.
|
Ó rán àwọn ẹrú rẹ̀ lọ pe àwọn tí ó dájọ́ igbeyawo náà fún, ṣugbọn wọn kò fẹ́ wá.
|
1.215895
|
Wagize abagabo batanu kandi n'uwo ufite ubu si umugabo wawe."
|
nítorí o ti ní ọkọ marun-un rí, ẹni tí o wà lọ́dọ̀ rẹ̀ nisinsinyii kì í sì í ṣe ọkọ rẹ.
|
1.215628
|
Ngo yaje "ari umugabo wo guhamya iby'urumuri kugira ngo bose bamukeshe kwemera."
|
Òun ni ó wá gẹ́gẹ́ bí ẹlẹ́rìí, kí ó lè jẹ́rìí sí ìmọ́lẹ̀ náà, kí gbogbo eniyan lè torí ẹ̀rí rẹ̀ gbàgbọ́.
|
1.215154
|
(Nk uko yavugiye mu kanwa k abera bayo, Bahanuraga uhereye kera kose.)
|
gẹ́gẹ́ bí ó ti sọ láti ẹnu àwọn wolii rẹ̀ mímọ́,láti ọjọ́ pípẹ́;
|
1.215008
|
Nuko abwira Labani ati "ibyo wankoreye ni ibiki?
|
Ó sì wí fún Labani pé, "Èwo ni ìwọ ṣe sí mi yìí?
|
1.213995
|
Harimpamvu Imana yaguhaye abo no kubushake bwabo yazaguha umuhungu yipfuza.
|
Ati awọn ti o ti pa rẹ ãnu nla fun u, ati awọn ti o ti fi ọmọ kan fun u joko lori itẹ rẹ, gẹgẹ bi o ti jẹ oni yi.
|
1.213813
|
Kandi urubyaro rwawe, ni rwo amahanga yose y'isi azifurizanyamo umugisha, kuko wumviye ijambo ryanjye."
|
"Gbogbo orílẹ̀-èdè tó wà láyé yóò gba ìbùkún fún ara wọn nípasẹ̀ ọmọ rẹ torí pé o fetí sí ohùn mi"
|
1.213605
|
Ni mu ijuru cyangwa se ni ku bantu?"
|
Láti ọ̀run wá ni, tàbí láti ọ̀dọ̀ ènìyàn."
|
1.213072
|
Utanga Uha uwo ashatse mu biremwa ibyo ashatse mu bigega bye,
|
ғîëèá á¢ëìîқ - to win
|
1.212304
|
Ibintu nk'ibi hari ibyigeze bibaho, ari mu gihe cyanyu, cyangwa se mu gihe cy'abasokuruza banyu?
|
Ǹjẹ́ irú ìṣẹ̀lẹ̀ yìí ti ṣẹlẹ̀ rí ní àkókò yín,tabi ní àkókò àwọn baba yín?
|
1.212086
|
Izina ry'Imana ritukwa mu bapagani ku bwanyu, nk'uko byanditswe'.
|
Ó wà ní àkọsílẹ̀ pé, "Orúkọ Ọlọrun di ohun ìṣáátá láàrin àwọn tí kì í ṣe Juu nítorí yín."
|
1.21205
|
Nta rindi tegeko riruta ayoyombi."
|
Ko si ofin miiran ti o tobi ju iwọn wọnyi lọ. "
|
1.212007
|
Iyaba Israheli yagenderaga mu nzira zanjye,
|
bí Israẹli yóò bá tẹ̀lé ọ̀nà mi,
|
1.211593
|
Ese koko ubutumwa bwiza bwaturutse ku Mana?
|
Ṣé Ọ̀dọ̀ Ọlọ́run Ni Ìròyìn Ayọ̀ Ti Wá Lóòótọ́? | Ìròyìn Ayọ̀
|
1.211394
|
Bageze imuhira, abantu benshi bongera guterana, bituma badashobora kugira icyo barya.
|
Lẹ́yìn náà, Jesu wọ inú ilé lọ, àwọn eniyan tún pé jọ tóbẹ́ẹ̀ tí òun ati àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ kò fi lè jẹun.
|
1.211314
|
Ntuzi ko mfite ububasha bwo kukurekura nkagira n'ubwo kukubambisha?"
|
O kò mọ̀ pé mo ní àṣẹ láti dá ọ sílẹ̀, mo sì ní àṣẹ láti kàn ọ́ mọ́ agbelebu?
|
1.211253
|
Muzi kureba uko ijuru risa mugasobanukirwa ibyaryo, ariko ibimenyetso by'ibihe ntimushobora kubisobanukirwa" (Matayo 16:2, 3).
|
' Ẹ mọ ohun tí àmì ojú ọ̀run jẹ́, ṣugbọn ẹ kò mọ àwọn àmì àkókò yìí.
|
1.21106
|
Yesu yaravuze ati "uzihangana akageza ku iherezo ni we uzakizwa."
|
Jésù sọ pé: "Ẹni tí ó bá fara dà á dé òpin ni ẹni tí a ó gbà là."
|
1.210832
|
Reka inshuti yanjye George abisobanure.
|
Ẹ jẹ́ kí ọ̀rẹ́ mi George ṣàlàyé.
|
1.210401
|
32Basigara bavugana bati: "Mbese imitima yacu ntiyari ikeye igihe yatuvugishaga turi mu nzira, adusobanurira Ibyanditswe?"
|
24:32 Nwọn si sọ fun ara wọn, "Ṣe ọkan wa ko jo laarin wa, lakoko ti o n sọrọ ni ọna, ati nigbati o ṣi Iwe Mimọ fun wa?"
|
1.210399
|
"Tubwire, ibyo bizaba ryari?"
|
"Sọ fún Wa, Ìgbà Wo Ni Nǹkan Wọ̀nyí Yóò Ṣẹlẹ̀?"
|
1.21013
|
Buri gihe azajya agufasha nk'uko yafashije Yeremiya.
|
Nígbà gbogbo ni yóò máa ràn ẹ́ lọ́wọ́, bó ṣe ran Jeremáyà lọ́wọ́.
|
1.210126
|
Ese mwizera ko ari mwe mwenyine muzakizwa?
|
Ṣé Ẹ Rò Pé Ẹ̀yin Nìkan Ló Máa Rí Ìgbàlà?
|
1.209885
|
12aKubera iyo mpamvu, ijuru niryishime, namwe abarituye munezerwe !"
|
12 Nitorina ẹ mã yọ̀, ẹnyin ọrun, ati ẹnyin ti ngbé inu wọn. .
|
1.209609
|
Muragowe igihe cyose abantu babavuga neza, kuko ari uko ababyeyi babo bagenzerezaga abahanuzi b'ibinyoma."
|
"Nígbà tí gbogbo eniyan bá ń ròyìn yín ní rere, ẹ gbé, nítorí bẹ́ẹ̀ ni àwọn baba wọn ṣe sí àwọn èké wolii.
|
1.208913
|
Ni nde muri yo wari wamenyekanyije ibi bikorwa, agatuma twumva ibyabayeho mbere?
|
Tani ninu yin ti yoo kede eyi, ati tani yoo mu wa gbọ ohun ti o jẹ akọkọ?
|
1.208113
|
14 Muri mwe harih'urwaye?
|
14Ẹnikẹ́ni ha ṣe àìsàn nínú yín bí?
|
1.208091
|
Baravuze bati "aya si amagambo y'umuntu ufite umudayimoni.
|
Àwọn mìíràn ń sọ pé, "Èyí kì í ṣe ọ̀rọ̀ ẹni tí ó ní ẹ̀mí èṣù.
|
1.208057
|
7Ni nde uhwanye nanjye?
|
7 Ta ni ó dàbí ì mi?
|
1.206838
|
Iyaba lsraheli yagenderaga mu nzira zanjye,
|
bí Israẹli yóò bá tẹ̀lé ọ̀nà mi,
|
1.206826
|
"Uko ni ko bamwe muri mwe mwari mumeze"
|
"Ohun Tí Àwọn Kan Lára Yín Ti Jẹ́ Rí Nìyẹn"
|
1.206571
|
Yaravuze ati "mu mugi umwe hari umucamanza utaratinyaga Imana kandi ntagire umuntu yubaha.
|
Ó ní, "Adájọ́ kan wà ní ìlú kan tí kò bẹ̀rù Ọlọrun, tí kò sì ka ẹnikẹ́ni sí.
|
1.206532
|
Ni ukuri nta mukiranutsi uri mu isi, ukora neza ntacumure.
|
"Dájúdájú, nibẹ ni ko kan olododo enia lori ile ti ṣe rere ti ko si dese."
|
1.20616
|
Uko Gayo yafashije abavandimwe be
|
Bí Gáyọ́sì Ṣe Ran Àwọn Ará Lọ́wọ́
|
1.206119
|
Ukuboza 2013 _ Ese dukeneye Imana?
|
DECEMBER 2013 Ǹjẹ́ A Nílò Ọlọ́run?
|
1.205878
|
Nanjye ndahamya ko batanze ku bwende bwabo, ndetse birenze uko bashoboye.
|
Nítorí mo jẹ́rìí pé wọ́n sa ipá wọn, wọ́n tilẹ̀ ṣe tayọ agbára wọn, tìfẹ́tìfẹ́ ni wọ́n sì fi ṣe é.
|
1.205572
|
*Mbese uri wawundi ugomba kuza , cyangwa dutegereze undi ?
|
"Ṣé ìwọ ni ẹni tí ó ń bọ̀ ni, tabi kí á máa retí ẹlòmíràn?
|
1.205348
|
8Igishuko nk'icyo nticyaturuka ku Uwabahamagaye.
|
8 Iyipada yi kò ti ọdọ ẹniti o pè nyin wá.
|
1.20473
|
Tugure twe n'ubutaka bwacu; uduhe icyo kurya, twe n'ubutaka bwacu tuzaba imbata za Farawo.
|
Fi oúnjẹ ra àwa ati ilẹ̀ wa, a óo sì di ẹrú Farao.
|
1.20459
|
Ahubwo nk uko uwabahamagaye ari uwera, abe ari ko namwe muba abera mu ngeso zanyu zose.
|
Ṣugbọn gẹ́gẹ́ bí ẹni tí ó pè yín ti jẹ́ mímọ́, bẹ́ẹ̀ ni kí ẹ̀yin náà jẹ́ mímọ́ ninu gbogbo ìwà yín.
|
1.204436
|
Nuko wandike ibyo ubonye n ibiriho, n ibiri bukurikireho hanyuma
|
Nítorí náà kọ àwọn ohun tí o rí sílẹ̀, ati àwọn ohun tí ó wà nisinsinyii ati àwọn ohun tí yóo ṣẹlẹ̀ lẹ́yìn ọ̀la.
|
1.204298
|
Ahubwo nk'uko uwabahamagaye ari Uwera, abe ari ko namwe muba abera mu ngeso zanyu zose.
|
Ṣugbọn gẹ́gẹ́ bí ẹni tí ó pè yín ti jẹ́ mímọ́, bẹ́ẹ̀ ni kí ẹ̀yin náà jẹ́ mímọ́ ninu gbogbo ìwà yín.
|
1.20402
|
Umwijima nzawuhindura umucyo imbere yazo, n'ahagoramye nzahagorora .
|
N óo sọ òkùnkùn di ìmọ́lẹ̀ níwájú wọn,n óo sì sọ àwọn ibi tí ó rí pálapàla di títẹ́jú.
|
1.203853
|
Ubwo wibagiwe amategeko y'Imana yawe, nanjye nzibagirwa abana bawe.
|
Nítorí pé ẹ ti gbàgbé òfin Ọlọrun yín, èmi náà yóo gbàgbé àwọn ọmọ yín.
|
1.20383
|
Mbese none roho yaba yaravuganye na we, cyangwa se umumalayika ?"
|
Ohun ti o ba a ẹmí ti sọ fun u, tabi angẹli?"
|
1.203336
|
Abantu bose na bo babibonye, basingiza Imana.
|
Gbogbo àwọn eniyan rí i tí ó ń rìn, tí ó ń yin Ọlọrun.
|
1.203325
|
Nta muntu n'umwe bazabona wo kubahamba, ari bo ubwabo, abagore babo, abahungu babo n'abakobwa babo.
|
Kò ní sí ẹni tí yóo sin òkú wọn, ati ti àwọn iyawo wọn, ati ti àwọn ọmọ wọn lọkunrin ati lobinrin.
|
1.203247
|
Nikodemo aramubaza ati "Mbese umuntu yabasha ate kubyarwa akuze?
|
Nikodemu bi í pé, "Báwo ni a ti ṣe lè tún ẹni tí ó ti di àgbàlagbà bí?
|
1.203202
|
Ese koko ubutumwa bwiza bwaturutse ku Mana?
|
Ṣé Ọ̀dọ̀ Ọlọ́run Ni Ìròyìn Ayọ̀ Ti Wá Lóòótọ́?
|
1.202554
|
"Twahangana dute n'ingorane duhura na zo mu mwaka wa mbere w'ishyingiranwa?"
|
"Báwo lo ṣe lè borí àwọn ìṣòro tó máa ń wáyé ní ọdún àkọ́kọ́ ìgbéyàwó?"
|
1.202516
|
Ariko ubu tuzi ko imisozi ...
|
Ṣùgbọ́n nísinsìnyí, a mọ̀ pé àwọn òkè ń...
|
1.201391
|
Nk'uko imyambi mu ntoki z'umunyembaraga iri, ni ko abana bo mu busore bamera.
|
Bí ọfà ti rí ní ọwọ́ alágbára, bẹ́ẹ̀ ni àwọn ọmọ èwe.
|
1.201354
|
8 Jyewe Yohana, ni jye wumvise ibyo bintu kandi ndabibona.
|
8 Emi Johanu li ẹniti o gbọ́ ti o si ri nkan wọnyi.
|
1.201106
|
Nawe Yuda, rwose nkugire nte?
|
Kí ni kí n ti ṣe ọ́ sí, ìwọ Juda?
|
1.201019
|
Wazanywe no kuduturumbanya igihe kitaragera?"
|
Ṣé o dé láti wá dà wá láàmú ṣáájú àkókò wa ni?"
|
1.200979
|
Ni ryali twakubonye urwaye cyangwa uri imbohe turagusura ? "
|
Nígbà wo ni a rí ọ tí o ṣàìsàn, tabi tí o wà lẹ́wọ̀n, tí a wá sọ́dọ̀ rẹ?
|
1.200858
|
Twibuke ko uko byari biri mu minsi ya Nowa ari ko bizamera mu kuza k'Umwana w'umuntu.
|
Àní bí ó ti rí ní àkókò Noa, bẹ́ẹ̀ ni yóo rí nígbà tí Ọmọ-Eniyan bá dé.
|
1.200463
|
Ngiye kumuha umufasha wo kumubera icyuzuzo."
|
Èmi yóò ṣe olùrànlọ́wọ́ tí ó rí bí i rẹ̀ fún un."
|
1.200438
|
Imana ikoresha uwo ishatse, ikamukoresha igihe ishakiye, ikamukoreshereza aho ishatse.
|
Ҡàï-ҡàðà ҡàí àҡҡàí, òè;
|
1.200346
|
Ariko nihagira urahira zahabu yo mu rusengero, azaba agomba kubahiriza indahiro ye."
|
Ṣugbọn bí eniyan bá fi wúrà tí ó wà ninu Tẹmpili búra, olúwarẹ̀ níláti mú ìbúra rẹ̀ ṣẹ.
|
1.200297
|
Yaba Farawo na Thamuda.
|
85:18 ti Farao, ati ti Thamood ?
|
1.20025
|
No. 6 2017 _ Ese isi yarenze igaruriro?
|
No. 6 2017 | Ṣé Ayé Yìí Ti Bà Jẹ́ Kọjá Àtúnṣe?
|
1.200233
|
Igihugu se cyabyarwa umunsi umwe gusa, cyangwa ihanga rikagira ritya rikavuka ?
|
Ǹjẹ́ a lè bí ilẹ̀ ní ọjọ́ kan,tabi kí á bí orílẹ̀-èdè kan ní ọjọ́ kan?
|
1.200189
|
Uba rero muri jye, nanjye nkaba muri we, yera imbuto nyinshi."
|
Ẹnikẹni ti o ba ngbé inu mi, ati emi ninu rẹ, si so ọpọlọpọ eso.
|
1.199909
|
Kandi ufite ibyo byiringiro muri we, yiboneza nk'uko uwo aboneye.
|
Gbogbo ẹni tí ó bá ní ìrètí yìí ninu Jesu yóo wẹ ara rẹ̀ mọ́ gẹ́gẹ́ bí Jesu fúnrarẹ̀, ti jẹ́ mímọ́.
|
1.19984
|
Abakobwa baturutse impande zose z'isi baragutegereje!
|
Awọn ọmọbirin lati gbogbo agbala aye n duro de ọ tẹlẹ!
|
1.199728
|
Nta wigeze azamuka ajya mu ijuru, uretse Umwana w'umuntu wamanutse aturutse mu ijuru.
|
Kò sí ẹni tí ó tíì gòkè lọ sí ọ̀run rí àfi ẹni tí ó ti ọ̀run sọ̀kalẹ̀ wá, èyí ni Ọmọ-Eniyan.
|
1.199725
|
36Abayahudi baravuga bati "Nimurebe ukuntu yamukundaga."
|
36 Àwọn Juu sọ fún un pé, "Wo bí ó ṣe fẹràn rẹ!"
|
1.199293
|
maze ntibakurikize amabwiriza yanjye,
|
tí wọn kò sì pa àṣẹ mi mọ́,
|
1.199177
|
Ni cyo cyatumye ngira igisibya kenshi kimbuza kuza iwanyu,
|
Ìdí nìyí tí mo fi ní ìdènà nígbà pupọ láti wá sọ́dọ̀ yín.
|
1.199101
|
kandi nahamagaye umwana wanjye ngo ave mu Misiri.
|
mo sì pe ọmọ mi jáde láti Ejibiti wá.
|
1.19908
|
Nuko ibabarira uwo ishaka, kandi inangira umutima w uwo ishaka.
|
ïðè âûñîêîé ïëîòíîñòè ìîíòàæà, íå ïîçâîëÿþùåé íàíåñòè ìàðêèðîâêó âñåõ ñõåìíûõ îáîçíà÷åíèé ðÿäîì ñ ýëåìåíòàìè;
|
1.198636
|
Wazanywe no kuduturumbanya igihe kitaragera ?"
|
Ṣé o dé láti wá dà wá láàmú ṣáájú àkókò wa ni?"
|
1.19793
|
Intumwa ze yatoye cumi n'ebyiri nta kindi yazitoreye.
|
Ó yan méjìlá [12] nínú wọn láti jẹ́ àpọ́sítélì.
|
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.