score
float32 1.04
1.25
| Rundi
stringlengths 9
496
| Yoruba
stringlengths 9
496
|
|---|---|---|
1.249829
|
Ibicumuro vyabo n'ivyaha vyabo na vyo sinzoba nkivyibuka."
|
Ó tún ní, "N kò ní ranti ẹ̀ṣẹ̀ ati ìwà burúkú wọn mọ́.
|
1.249702
|
Yezu yongera ababwira ati: "Habaye umuntu yari afise abahungu babiri.
|
Jesu ní, "Ọkunrin kan ní ọmọ meji.
|
1.249504
|
Canke uwavyawe n'umugore, vyoshobka bite ko aba umugororotsi?
|
àti ẹni tí a tinú obìnrin bí tí yóò fi ṣe olódodo?
|
1.247733
|
Bashikibe bo ntibari aha muri twebwe?"
|
Àwọn arábìnrin rẹ̀ gbogbo ha kọ́ ni ó ń bá wa gbé níhìn-ín yìí?"
|
1.2437
|
Mu kuvuga akoresha ibimenyetso gusa.
|
Awọn yiyo nikan o gba o a diẹ aaya.
|
1.243542
|
Nanje ndababwiye ko ngaha hari uwuruta Igisengero.
|
Mo sọ fun yín pé ẹni tí ó ju Tẹmpili lọ ló wà níhìn-ín yìí.
|
1.242743
|
Uwifatanije n'Umukama aca asangira umutima na we.
|
Ṣugbọn ẹni tí ó bá ní ìdàpọ̀ pẹlu Oluwa di ọ̀kan pẹlu rẹ̀ ninu ẹ̀mí.
|
1.242373
|
Uwo muntu vyorushirije kumubera vyiza iyo ataba yaravutse."
|
Ìbá sàn fún ọkùnrin náà bí a kò bá bí i. "
|
1.241984
|
Twabonye inyenyeri yiwe iserutse, duca tuza kumusenga. "
|
Àwa ti rí ìràwọ̀ rẹ̀ ní ìlà-oòrùn, a sì wá láti foríbalẹ̀ fún un."
|
1.241787
|
Bamushikiriye bati: "Bose bariko barakurondera."
|
37Nígbà tí wọ́n sì rí I, wọ́n sọ fún wí pé, "Gbogbo ènìyàn ń wá ọ!"
|
1.241386
|
Ntizokwigera iduta nk'uko umugabo wanje yabigize."
|
Kò sì ní pa wá tì láé bí ọkọ mi ṣe pa wá tì."
|
1.240724
|
Kandi izokwubaka ibisagara vya Yuda,
|
yóò sì tún àwọn ìlú Juda wọ̀nyí kọ́.
|
1.240724
|
kandi izokwubaka ibisagara vya Yuda,
|
yóò sì tún àwọn ìlú Juda wọ̀nyí kọ́.
|
1.240376
|
Nta rindi tegeko riruta ayo yombi."
|
Ko si ofin miiran ti o tobi ju iwọn wọnyi lọ. "
|
1.23994
|
Bamushikiriye bati: "Bose bariko barakurondera."
|
37 Nígbà tí wọ́n sì rí I, wọ́n sọ fún wí pé, "Gbogbo ènìyàn ń wá ọ!"
|
1.23789
|
Umwe amuronka uko ashaka,
|
Бîðëóóëаëò áà óäèðäëàãûí çàðäëûí òoñoâ
|
1.237756
|
"Ukwo ni ko bamwe muri mwebwe bari bameze"
|
"Ohun Tí Àwọn Kan Lára Yín Ti Jẹ́ Rí Nìyẹn"
|
1.237161
|
Abasavyi b'Imana bari bakeneye cane gufashwa no gukingirwa.
|
Àwọn èèyàn Ọlọ́run nílò ìrànlọ́wọ́ àti ààbò gan-an.
|
1.237155
|
Abasavyi b'Imana bari bakeneye cane gufashwa no gukingirwa.
|
Àwọn èèyàn Ọlọ́run nílò ìrànlọ́wọ́ àti ààbò gan- an.
|
1.236731
|
30 Nzobirukana buhorobuhoro bakuve imbere, gushika urondotse, ukigarurira koko nya gihugu+.
|
30 Diẹdiẹ li emi o ma lé wọn jade kuro niwaju rẹ, titi iwọ o fi di pupọ̀, ti iwọ o si tẹ̀ ilẹ na dó.
|
1.235055
|
Abasavyi banje bazonezerwa, mugabo mwebwe muzokwicwa n'ibimaramare.
|
Àwọn iranṣẹ mi yóo máa yọ̀,ṣugbọn ìtìjú yóo máa ba yín.
|
1.234897
|
Kigarama 2013 _ Twoba dukeneye Imana?
|
DECEMBER 2013 Ǹjẹ́ A Nílò Ọlọ́run?
|
1.234611
|
Kumpatia vyovyote atakavyo.
|
ғîëèá á¢ëìîқ - to win
|
1.234317
|
Nzobana na we mu marushwa."
|
èmi yóò wà pẹ̀lú rẹ̀ nínú ìpọ́njú,
|
1.234008
|
Bavishije amaraso y'abera n'ay'abavugishwa nawe, kand.amaraso nyene niyo ubahaye ngo banywe, birababereye.
|
Wọ́n ta ẹ̀jẹ̀ àwọn eniyan rẹ ati àwọn wolii rẹ sílẹ̀, nítorí náà o fún wọn ní ẹ̀jẹ̀ mu.
|
1.232472
|
Nta n'inzu yari afise.
|
Kódà kò ní ilé tara ẹ̀.
|
1.232115
|
Ni kuki munyita ngo Mukama, Mukama, kandi mudakora ico mvuga?
|
"Kí ló dé tí ẹ̀ ń pè mí ní, 'Oluwa, Oluwa,' tí ẹ kì í ṣe ohun tí mo sọ?
|
1.23196
|
Ivyo murabigire munyibuka."
|
Ẹ máa ṣe èyí ní ìrántí mi.
|
1.230738
|
Ni igiki umuhanuzi yava i Yuda yananiwe gukora, kandi vyavuyemwo iki?
|
Kí ni wòlíì tó wá láti Júdà yẹn kò ṣe, kí ló sì yọrí sí?
|
1.230657
|
Yezu yavuze ati: "Uwihanganye gushika kw'iherezo ni we azokizwa."
|
Jésù sọ pé: "Ẹni tí ó bá fara dà á dé òpin ni ẹni tí a ó gbà là."
|
1.230289
|
" Ntimukomantaze imitima yanyu nka kera mu gahinga,
|
ẹ má ṣe agídí, gẹ́gẹ́ bíi ti àkókò ìṣọ̀tẹ̀,ní àkókò ìdánwò ninu aṣálẹ̀,
|
1.229787
|
Bisubiye, abahawe wa muhango, ni mwebwe n'abana banyu hamwe n'bari kure bose, eka abo bose Umukama Imana yacu izohamagara. "
|
Nítorí ẹ̀yin ni a ṣe ìlérí yìí fún, ati àwọn ọmọ yín ati gbogbo àwọn tí wọ́n wà ní ọ̀nà jíjìn; a ṣe é fún gbogbo ẹni tí Oluwa Ọlọrun wa bá pè.
|
1.229181
|
Iryo jwi twararyumvise rivuye mw'ijuru hamwe twari kumwe na We kuri wa musozi mweranda.
|
Àwa fúnra wa gbọ́ ohùn yìí nígbà tí ó wá láti ọ̀run nítorí a wà pẹlu rẹ̀ lórí òkè mímọ́ nígbà náà.
|
1.228897
|
Kukw'isezerano ar'iryanyu kand'ar'iry'abana banyu, n'abari kure bose, abazohamagarwa bose n'Umwami Imana yacu (Ivyakozwe n'Intumwa 2: 38-39).
|
Nítorí ẹ̀yin ni a ṣe ìlérí yìí fún, ati àwọn ọmọ yín ati gbogbo àwọn tí wọ́n wà ní ọ̀nà jíjìn; a ṣe é fún gbogbo ẹni tí Oluwa Ọlọrun wa bá pè.
|
1.228112
|
Ntazotongana canke ngo avuze urwamo, eka nta n'uwuzokwumva ijwi ryiwe mu mayira yagutse.
|
Kò ní ṣàròyé, bẹ́ẹ̀ ni kò ní pariwo,bẹ́ẹ̀ ni ẹnìkan kò ní gbọ́ ohùn rẹ̀ ní títì.
|
1.228097
|
Agira ati: "Mu gisagara kimwe hariho umucamanza umwe atatinya Imana akaba kandi atubaha umuntu.
|
Ó ní, "Adájọ́ kan wà ní ìlú kan tí kò bẹ̀rù Ọlọrun, tí kò sì ka ẹnikẹ́ni sí.
|
1.228061
|
Twibuke abari mu murimo w'igihe cose
|
Máa Rántí Àwọn Tó Ń Ṣe Iṣẹ́ Ìsìn Alákòókò Kíkún
|
1.227373
|
Imana ni yo nizigiye, nta co ngitinya.
|
nínú Ọlọ́run ni ìgbẹ́kẹ̀lé mi; ẹ̀rù kì yóò bà mí
|
1.227273
|
פ [Peʼ] 30 Akanwa k'umugororotsi ni ko kavuga ubukerebutsi n'ijwi ritoyi+,Kandi ururimi rwiwe ni rwo rucisha aho ukuri kuri+.
|
30 Ẹnu olododo ni ima sọ̀rọ ọgbọ́n, ahọn rẹ̀ a si ma sọ̀rọ idajọ.
|
1.22723
|
Umukama yaragukijije urubanza rwari rukugeramiye, yaragukuyeko umwansi wawe.
|
OLUWA ti mú ẹ̀bi yín kúrò,ó sì ti lé àwọn ọ̀tá yín lọ.
|
1.226933
|
Yemwe abemeye!
|
Eyin Onigbagbo ododo o!
|
1.22687
|
Mwoba mwemera ko ari mwebwe mwenyene muzorokoka?
|
Ṣé Ẹ Rò Pé Ẹ̀yin Nìkan Ló Máa Rí Ìgbàlà?
|
1.226848
|
Bomumenya bate, batagira uwabatumye?
|
Báwo ni àwọn kan yóo ṣe lọ kéde rẹ̀ láìjẹ́ pé a bá rán wọn lọ?
|
1.226577
|
Urupfu rwoba ruri mu mugambi Imana idufitiye?
|
Ṣé ìfẹ́ Ọlọ́run ni pé kí àwa èèyàn máa kú?
|
1.225727
|
Ni co gituma abavyeyi biwe bavuga bati: "Si muto, nimumwibarize!"
|
Nítorí èyí ni àwọn òbí ọkunrin náà ṣe sọ pé, "Kì í ṣe ọmọde, ẹ bi òun alára léèrè.
|
1.225683
|
"Muhava muvuga muti: tuzorya iki mu mwaka ugira inddwi ko tutazotera imbuto canke ngo dushwabure ivyimburwa vyacu?
|
"Bí ẹ bá ń wí pé, 'Kí ni a óo jẹ ní ọdún keje bí a kò bá gbọdọ̀ gbin ohun ọ̀gbìn, tí a kò sì gbọdọ̀ kórè?
|
1.225485
|
Nta jambo na rimwe muri yo ritashitse."
|
Kò sí ọ̀rọ̀ kan lára wọn tí ó kùnà."
|
1.225313
|
Muzobona ibara ah'abantu bose bazobashemagiza; kukw'ari ko ba sekuruza babo bashemagije abigira abavugishwa n'Imana " (Luka 6:24-26).
|
"Nígbà tí gbogbo eniyan bá ń ròyìn yín ní rere, ẹ gbé, nítorí bẹ́ẹ̀ ni àwọn baba wọn ṣe sí àwọn èké wolii.
|
1.225207
|
(Zaburi 55:22) Ivyo nyene ni vyo ngerageza gukora buri musi.
|
(Sáàmù 55:22) Ohun tí mo máa ń gbìyànjú láti ṣe lójoojúmọ́ nìyẹn.
|
1.224439
|
Maze amahanga yose azokoranirizwa imbere yiwe; na we azotandukanya abantu n'abandi, nka kurya umwungere atandukanya intama n'impene."
|
Gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè yóo péjọ níwájú rẹ̀, yóo wá yà wọ́n sọ́tọ̀ọ̀tọ̀, bí olùṣọ́-aguntan tíí ya àwọn aguntan sọ́tọ̀ kúrò lára àwọn ewúrẹ́.
|
1.223777
|
Nzoyibwira abagenzi banje."
|
Àwọn ọ̀rẹ́ mi ni màá sọ fún."
|
1.223606
|
Nk'akarorero, reka dusuzume ivyerekeye Noweli.
|
Bí àpẹẹrẹ, wo Kérésìmesì.
|
1.223588
|
ICIGWA CA 3 Iyo nkuru nziza yoba vy'ukuri iva ku Mana?
|
Ẹ̀KỌ́ 03--Ṣé Ọ̀dọ̀ Ọlọ́run Ni Ìròyìn Ayọ̀ Ti Wá Lóòótọ́?
|
1.223551
|
Azovyara abatware icumi na babiri kandi nzomugira igihugu gihambaye.
|
O si yoo gbe awọn mejila olori, emi o si sọ ọ di orilẹ-ède nla.
|
1.223488
|
Mu misi yiwe umugororotsi azonaga, kandi hazobaho amahoro menshi gushika ukwezi kutakiriho.
|
Kí ìwà rere ó gbèrú ní ìgbà tirẹ̀;kí alaafia ó gbilẹ̀ títítí òṣùpá kò fi ní yọ mọ́.
|
1.223433
|
Ntiyigera asiba ku rusengero.
|
Kì í fi ìgbà kan kúrò ninu Tẹmpili.
|
1.223247
|
Uwo yahereye mu ntango ari umwicanyi, kandi ntiyahagaze mu kuri, kuko ata kuri kuri muri we.
|
O je apaniyan lati ibẹrẹ, ko si duro ninu otitọ, nitori ko si otitọ ninu rẹ.
|
1.223087
|
Mu rugo kwa Nowa rero haba abantu umunani.
|
Nítorí náà, èèyàn mẹ́jọ ló wà nínú ìdílé Nóà.
|
1.222328
|
Bene Data, ni mwirinde ntihagire uwo muri mwebwe agira umutima mubi utizera, umutera kurek'Imana nzima.
|
Ẹ kíyèsára, ará, kí ó má ṣe sí ẹnikẹ́ni ninu yín tí yóo ní inú burúkú tóbẹ́ẹ̀ ti kò ní ní igbagbọ, tí yóo wá pada kúrò lẹ́yìn Ọlọrun alààyè.
|
1.221601
|
Yamara mweho rero muragowe, mwebwe batunzi,
|
"Ṣugbọn ẹ̀yin ọlọ́rọ̀ gbé,nítorí ẹ ti jẹ ìgbádùn tiyín tán!
|
1.220727
|
Henoki ashobora kuba yaribaza nimba yokwigeze asubira kubona umuryango wiwe.
|
Ó tiẹ̀ ṣeé ṣe kí Énọ́kù ti máa rò ó pé bóyá lòun á fojú kan ìdílé òun mọ́.
|
1.219607
|
20 Mu vy'ukuri ni mwebwe buninahazwa bwacu n'akanyamuneza kacu.
|
Ṣé ẹ̀yin kọ́ ni? 20 Nítòótọ́, ẹ̀yin ni ògo àti ayọ̀ wa.
|
1.219525
|
Umusi w'Urubanza ni iki?
|
Kí Ni Ọjọ́ Ìdájọ́?
|
1.218993
|
Azokwama agufasha, nk'uko yafashije Yeremiya.
|
Nígbà gbogbo ni yóò máa ràn ẹ́ lọ́wọ́, bó ṣe ran Jeremáyà lọ́wọ́.
|
1.218823
|
Hoba hari ikibanza mu nzu ya so tworaramwo?"
|
Sọ fun mi, ibi kankan wa ni ile baba rẹ lati wọ̀?"
|
1.218736
|
Canke ugize ijisho ribi kubera ko ndi umuntu mwiza?'
|
Tabi ni oju rẹ buburu nitori emi o dara?'
|
1.21865
|
Bavishije amaraso y'abera n'ay'abavugishwa nawe, kand.amaraso nyene niyo ubahaye ngo banywe, [...]
|
Wọ́n ta ẹ̀jẹ̀ àwọn eniyan rẹ ati àwọn wolii rẹ sílẹ̀, nítorí náà o fún wọn ní ẹ̀jẹ̀ mu.
|
1.218043
|
Imana yoba izi ibizoba?
|
Ǹjẹ́ Ọlọ́run Mọ Ọjọ́ Ọ̀la?
|
1.218005
|
Ishengero ryose ngo ribibone, rishemeza Imana.
|
Gbogbo àwọn eniyan rí i tí ó ń rìn, tí ó ń yin Ọlọrun.
|
1.217843
|
Ibintu vy'agaciro n'ubutunzi biri mu nzu yiwe, kandi ubugororotsi bwiwe bwamaho ibihe bidahera."
|
Ọlá ati ọlà yóo wà ní ilé rẹ̀,Òdodo rẹ̀ wà títí lae.
|
1.217538
|
Ntimuzi ko ntegerezwa kuba ndi mu ngoro ya Data?'
|
Nitori iwọ kò mọ pe o pọndandan fun mi lati wà ninu iwọnyi ti o jẹ ti Baba mi?"
|
1.21749
|
Ntuzi ko nari gushobora gusaba Data akandungikira ubwo nyene Abamarayika ibihumbi n'ibihumbi b'ukuntabara ?
|
Tabi o kò mọ̀ pé mo lè ké pe Baba mi, kí ó fún mi ní ẹgbaagbeje angẹli nisinsinyii?
|
1.217212
|
Ntuzi ko nari gushobora gusaba Data akandungikira ubwo nyene Abamarayika ibihumbi n'ibihumbi b'ukuntabara ?
|
53Ìwọ kò mọ̀ pé èmi lè béèrè lọ́wọ́ Baba mi kí ó fún mi ju légíónì (6,000) angẹli méjìlá?
|
1.216568
|
Yesu arabaza: " Kandi munyitira iki 'Mwami, Mwami;' ntimukore ivyo mvuga? "
|
"Kí ló dé tí ẹ̀ ń pè mí ní, 'Oluwa, Oluwa,' tí ẹ kì í ṣe ohun tí mo sọ?
|
1.215946
|
Ariko muritwo nta na kamwe gakorokera haso So atabizi.
|
Ati pe ko si ọkan ninu wọn ti yoo ṣubu lulẹ laisi Baba rẹ.
|
1.215863
|
Yavuze ati: "Ndakwinginze unzanire utuzi dukeyi mu kintu kugira ngo nywe."
|
On si wi fun u pe, "Fun mi ni omi kekere ninu omi, kí n lè mu. "
|
1.215648
|
Ingene Gayo yafashije abavukanyi
|
Bí Gáyọ́sì Ṣe Ran Àwọn Ará Lọ́wọ́
|
1.215569
|
Wewe ufise amajambo y'ubuzima budahera."
|
Ìwọ ni ó ni ọ̀rọ̀ ìyè àìnípẹ̀kun.
|
1.215335
|
Nimutabaze izina ry'imana yanyu, mugabo ntimubishireko umuriro."
|
Ki o si pe awọn orukọ ti awọn oriṣa rẹ, ṣugbọn máṣe fi iná si abẹ rẹ̀. "
|
1.215034
|
ibiketogi gibedo rwodi i lobo ducu.
|
Iwọ o fi idi wọn mulẹ bi awọn olori lori gbogbo ilẹ.
|
1.213647
|
N'ishengero ryose ry'abantu riramubona agenda ashimagiza Imana.
|
Gbogbo àwọn eniyan rí i tí ó ń rìn, tí ó ń yin Ọlọrun.
|
1.213356
|
Imana yatoye nde ngo abe Umutware w'Ubwami bwayo, kandi ni gute ivyo vyari vyaravuzwe?
|
Ta ni Ọlọ́run yàn ṣe Ọba Ìjọba Rẹ̀, báwo sì ni Bíbélì ṣe sọ èyí tẹ́lẹ̀?
|
1.213227
|
Na we uwo wese afise ako gatima k'ukumwizigira, ni mweranda nk'uko na We ari mweranda.
|
Gbogbo ẹni tí ó bá ní ìrètí yìí ninu Jesu yóo wẹ ara rẹ̀ mọ́ gẹ́gẹ́ bí Jesu fúnrarẹ̀, ti jẹ́ mímọ́.
|
1.212994
|
Nimwigaye, kandi mwizere inkuru nziza."
|
Ronupiwada ki o si gbagbo ninu Ihinrere. "
|
1.212892
|
Baranuma, kubera ko bari bamye baharīra ngo bamenye umukuru muri bo uwo ari we.
|
Wọ́n bá dákẹ́ nítorí ní ọ̀nà, wọ́n ti ń bá ara wọn jiyàn lórí ta ni ó ṣe pataki jùlọ.
|
1.212811
|
Kwipfuza kuba ari wenyene canke kuba kumwe n'abantu bakeyi cane.
|
Ó máa ń wù wọ́n kí wọ́n dá wà tàbí kó jẹ́ ìwọ̀nba èèyàn díẹ̀ ló máa wà lọ́dọ̀ wọn.
|
1.212585
|
Twoba dushobora kumenya ukuri kwerekeye Imana?
|
Ṣé A Lè Mọ Ohun Tó Jẹ́ Òtítọ́ Nípa Ọlọ́run?
|
1.212443
|
Kandi Imana izohanagura amosozi yose ku maso yabo."
|
'Ọlọ́run yóò sì nu omijé gbogbo nù kúrò ni ojú wọn.' "
|
1.21241
|
Azoganza kuva kukiyaga gushika ku kindi, kuva ku ruzi gushika ku mpera y'isi.
|
Kí ìjọba rẹ̀ ó lọ láti òkun dé òkun,ati láti odò ńlá títí dé òpin ayé.
|
1.21237
|
Twebwe turi ibumba, nawe uri Umubumvyi wacu; kandi twese turi igikorwa c'ukuboko kwawe."
|
Iwọ si ni Olupilẹṣẹ wa, gbogbo wa li iṣẹ ọwọ rẹ.
|
1.211918
|
Umuntu ni yavuga,ati nkunda IMANA,akanka mwene Data wundi,aba ar'umubeshi.kuk'udakunda mwene Data yabonye ntashobora gukunda IMANA atabonye.
|
20 Bi ẹnikẹni ba wipe, Emi fẹran Ọlọrun, ti o si korira arakunrin rẹ̀, eke ni: nitori ẹniti kò fẹran arakunrin rẹ̀ ti o ri, bawo ni yio ti ṣe le fẹran Ọlọrun ti on kò ri? 21 Ofin yi li awa si ri gbà lati ọwọ́ rẹ̀ wá, pe ẹniti o ba fẹran Ọlọrun ki o fẹran arakunrin rẹ̀ pẹlu.
|
1.211705
|
Imana yoba vy'ukuri yitaho abakenyezi?
|
(trg) ="1"> Ǹjẹ́ Ọ̀rọ̀ Àwọn Obìnrin Tiẹ̀ Jẹ Ọlọ́run Lógún ?
|
1.211648
|
Naho weho wovyibagira, jeho sinzokwibagira."
|
Lõtọ, nwọn le gbagbe, ṣugbọn emi kì yio gbagbe rẹ."
|
1.211004
|
Ivyo rero bazobibagirira kuko batazi Data, na Jewe nyene ntibamenye.
|
Wọn yóo ṣe nǹkan wọnyi nítorí wọn kò mọ Baba, wọn kò sì mọ̀ mí.
|
1.210989
|
Mugukira kwawe , ugira amasezerano ava ku Mana, ku bana bawe n'abawe bose n'abari kure bose bahamagawe n'Umwami Imana.
|
Nítorí ẹ̀yin ni a ṣe ìlérí yìí fún, ati àwọn ọmọ yín ati gbogbo àwọn tí wọ́n wà ní ọ̀nà jíjìn; a ṣe é fún gbogbo ẹni tí Oluwa Ọlọrun wa bá pè.
|
1.21086
|
yari umusaserdoti mukuru uyo mwaka.
|
Ate le tun mu sadaxalasibaxa kuntigiba ti wo san.
|
1.210629
|
Igihe umuhanuzi w'Imana Samweli yateba gushika i Gilugali ku gihe cashinzwe, Sauli yarabuze ukwihangana.
|
Nígbà kan tí wòlíì Sámúẹ́lì kò tètè dé sí ìlú Gílígálì níbi tí wọ́n fàdéhùn sí, Sọ́ọ̀lù ṣe ohun tí kò yẹ kó ṣe.
|
1.210175
|
Ko werekanye ko uri umwizigirwa mu kintu gitoyi cane, nugire ububasha ku bisagara cumi.'
|
Nítorí tí ìwọ ṣe olóòtítọ́ ní ohun kínkínní, gba àṣẹ lórí ìlú mẹ́wàá.'
|
1.210113
|
"Nta muntu n'umwe azoshobora kuguhagarara imbere imisi yose uzomara ukiriho: nk'uko nabanye na Mose ni ko nzobana nawe; sinzoguhemukira, sinzoguta.
|
5 Ẹnikẹ́ni kì yóò mú ìdúró gbọn- in gbọn- in níwájú rẹ ní gbogbo ọjọ́ ayé rẹ.+ Gan- an gẹ́gẹ́ bí mo ti wà pẹ̀lú Mósè ni èmi yóò ṣe wà pẹ̀lú rẹ.+ Èmi kì yóò kọ̀ ọ́ tì, bẹ́ẹ̀ ni èmi kì yóò fi ọ́ sílẹ̀ pátápátá.+
|
1.209606
|
Gatanzwe mu bijanye n'igikorwa kirangurirwa kw'isi yose c'ukwigisha Bibiliya gishigikirwa n'intererano zitangwa n'abavyishakiye.
|
(trg) ="3"> Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn .
|
Rundi-Yoruba_Sentence-Pairs Dataset
This dataset contains sentence pairs for African languages along with similarity scores. It can be used for machine translation, sentence alignment, or other natural language processing tasks.
This dataset is based on the NLLBv1 dataset, published on OPUS under an open-source initiative led by META. You can find more information here: OPUS - NLLB-v1
Metadata
- File Name: Rundi-Yoruba_Sentence-Pairs
- Number of Rows: 174926
- Number of Columns: 3
- Columns: score, Rundi, Yoruba
Dataset Description
The dataset contains sentence pairs in African languages with an associated similarity score. Each row consists of three columns:
score: The similarity score between the two sentences (range from 0 to 1).Rundi: The first sentence in the pair (language 1).Yoruba: The second sentence in the pair (language 2).
This dataset is intended for use in training and evaluating machine learning models for tasks like translation, sentence similarity, and cross-lingual transfer learning.
References
Below are papers related to how the data was collected and used in various multilingual and cross-lingual applications:
[1] Holger Schwenk and Matthijs Douze, Learning Joint Multilingual Sentence Representations with Neural Machine Translation, ACL workshop on Representation Learning for NLP, 2017
[2] Holger Schwenk and Xian Li, A Corpus for Multilingual Document Classification in Eight Languages, LREC, pages 3548-3551, 2018.
[3] Holger Schwenk, Filtering and Mining Parallel Data in a Joint Multilingual Space ACL, July 2018
[4] Alexis Conneau, Guillaume Lample, Ruty Rinott, Adina Williams, Samuel R. Bowman, Holger Schwenk and Veselin Stoyanov, XNLI: Cross-lingual Sentence Understanding through Inference, EMNLP, 2018.
[5] Mikel Artetxe and Holger Schwenk, Margin-based Parallel Corpus Mining with Multilingual Sentence Embeddings arXiv, Nov 3 2018.
[6] Mikel Artetxe and Holger Schwenk, Massively Multilingual Sentence Embeddings for Zero-Shot Cross-Lingual Transfer and Beyond arXiv, Dec 26 2018.
[7] Holger Schwenk, Vishrav Chaudhary, Shuo Sun, Hongyu Gong and Paco Guzman, WikiMatrix: Mining 135M Parallel Sentences in 1620 Language Pairs from Wikipedia arXiv, July 11 2019.
[8] Holger Schwenk, Guillaume Wenzek, Sergey Edunov, Edouard Grave and Armand Joulin CCMatrix: Mining Billions of High-Quality Parallel Sentences on the WEB
[9] Paul-Ambroise Duquenne, Hongyu Gong, Holger Schwenk, Multimodal and Multilingual Embeddings for Large-Scale Speech Mining, NeurIPS 2021, pages 15748-15761.
[10] Kevin Heffernan, Onur Celebi, and Holger Schwenk, Bitext Mining Using Distilled Sentence Representations for Low-Resource Languages
- Downloads last month
- 15