score
float32
1.04
1.25
Chichewa
stringlengths
10
500
Yoruba
stringlengths
9
498
1.217562
40:6 Ndipo pamene Yosefe analowa kwa iwo m'maŵa, ndipo anaona iwo zachisoni,
40:6 Ati nigbati Josefu si wọ fún wọn ní òwúrọ, o si ti ri wọn ìbànújẹ,
1.217343
Palibe lamulo lina loposa amenewa."
Ko si ofin miiran ti o tobi ju iwọn wọnyi lọ. "
1.21726
2Iye adzaweruza anthu anu mwachilungamo,
2 Yóò ṣe ìdájọ́ àwọn ènìyàn rẹ̀ pẹ̀lú òdodo,
1.217233
ndipo iwo amene amakonda dzina lake adzakhala kumeneko.
àwọn tí ó fẹ́ orúkọ rẹ ni yóò máa gbé inú rẹ̀.
1.217222
Inu mumadana ndi onse ochita zoyipa.
Ìwọ kórìíra gbogbo àwọn aṣebi;
1.216979
Kodi ine kwa iwe sindili woposa ana aamuna khumi?"
Emi kò ha dara lati ọ ju ọmọ mẹwa?"
1.216892
ndipo adzayenda mʼdzina lake,"
wọn ó sì rìn sókè rìn sódò ni orúkọ rẹ̀,"
1.216343
Kodi Mumakhulupirira Kuti Ndinu Nokha Amene Mudzapulumuke?
Ṣé Ẹ Rò Pé Ẹ̀yin Nìkan Ló Máa Rí Ìgbàlà?
1.216276
Anthu onse atamuona akuyenda ndiponso kuyamika Mulungu,
Gbogbo àwọn eniyan rí i tí ó ń rìn, tí ó ń yin Ọlọrun.
1.216253
inu ana a Yakobo, osankhidwa ake.
ẹ̀yin ọmọkùnrin Jakọbu, àyànfẹ́ rẹ̀.
1.215939
24 Ho! munthu wosauka ine!
24 Emi ẹni òsi!
1.215706
Ndidana nawo msonkhano wa ochimwa, ndipo sindidzakhala nawo pansi ochita zoipa."
5 Emi ti korira ijọ awọn oluṣe-buburu; emi kì yio si ba awọn enia buburu joko.
1.215476
6 Kuyambira pamene ndinabadwa, ndakhala ndikudalira Inu;
6 Mo gbẹ́kẹ̀lé ọ láti ìgbà ìbí mi;
1.21547
Ngati Yakobo kulandira mkazi pakati pa katundu wa dziko lino, Sindikadakhala okonzeka moyo. "
Ti Jakobu ba gba iyawo lati inu iṣura ilẹ yii, Emi ko ni fẹ lati wa laaye. "
1.215152
Koyamba kumva Taiwan?
Igba akọkọ ti n gbọ Taiwan?
1.215134
"Ndipo monga masiku a [Nowa] kotero kudzakhala kufika kwake kwa mwana wa munthu.
Àní bí ó ti rí ní àkókò Noa, bẹ́ẹ̀ ni yóo rí nígbà tí Ọmọ-Eniyan bá dé.
1.215111
40:6 Ndipo pamene Yosefe analowa kwa iwo m'maŵa, ndipo anaona iwo zachisoni,
40:6 Josefu si wọle tọ̀ wọn lọ li owurọ̀, o si ti ri wọn banujẹ,
1.215062
"Adalenga iwo mwamuna ndi mkazi; ndipo anawadalitsa, nawatcha dzina la Adamu, tsiku lomwe anawalengedwa. "
2 Ati akọ ati abo li o dá wọn; o si súre fun wọn, o si pè orukọ wọn ni Adamu, li ọjọ́ ti a dá wọn.
1.214962
39 Ndi liti pamene tinakuonani mukudwala kapena muli m'ndende ife n'kudzakuchezerani?'
39 Tabi nigbawo li awa ri ti iwọ ṣe aisan, ti a bojuto ọ? tabi ti iwọ wà ninu tubu, ti awa si tọ̀ ọ wá?
1.214921
Izi ndi Ayah (ndime) za buku ili (lomwe lasonkhanitsa chilichonse chofunika); ndipo chomwe chavumbulutsidwa kwa iwe kuchokera kwa Mbuye wako, nchoonadi; koma anthu ambiri sakhulupirira.
Ti eyi ti o ti rán si isalẹ lati o (Anabi Muhammad) lati rẹ Oluwa ni otitọ, sibe ọpọlọpọ awọn eniyan ma ko gbagbọ .
1.214907
Iye abvunza: 'Kodi iwe usafuna kuenda na ine pabodzi na Sila?
Ó ń béèrè pé: 'Ṣé wàá fẹ́ láti tẹ̀ lé èmi àti Sílà?
1.214845
Kodi wadza kwa ine kundikumbutsa tchimo langa, ndi kundiphera mwana wanga?"
Ṣé o wá sọ́dọ̀ mi láti rán Ọlọrun létí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ mi, ati láti ṣe ikú pa ọmọ mi ni.
1.214774
2Iye adzaweruza anthu anu mwachilungamo,
2Yóò ṣe ìdájọ́ àwọn ènìyàn rẹ̀ pẹ̀lú òdodo,
1.214743
Muli ndi tsoka pamene anthu onse akuyamikirani, pakuti makolo anu anachitila aneneri onama zomwezo.
"Nígbà tí gbogbo eniyan bá ń ròyìn yín ní rere, ẹ gbé, nítorí bẹ́ẹ̀ ni àwọn baba wọn ṣe sí àwọn èké wolii.
1.21446
"Iwowa sadzalowa ku malo anga a mpumulo."
'Wọn kì yóò wọ ibi ìsinmi mi.' "
1.214237
ndipo sanadziwe njira zanga."
wọn kò sì mọ ọ̀nà mi.'
1.214044
Nanga nʼchifukwa chiyani mukunena zimenezi kwa ine?"
Nítorí ki o si, idi ti yoo ti o sọ ọrọ yi fun mi?"
1.213898
17 "Ndikumuona iye koma osati tsopano;
17"Mo rí i, ṣùgbọ́n kì í ṣe ìsinsin yìí,
1.213712
4 Pontho tisakulemberani pinthu ipi toera kutsandzaya kwathu kudzadziswe.
À ń kọ àwọn nǹkan wọnyi si yín kí ayọ̀ wa lè kún.
1.213684
Ndiuzeni, pali malo aliwonse mu nyumba ya atate wako amchereze?"
Sọ fun mi, ibi kankan wa ni ile baba rẹ lati wọ̀?"
1.213658
Atumwiwo anayankha kuti: "Sitingathe ife kuleka kulankhula zimene tinaziona ndi kuzimva."
Awọn aposteli mejeji dahun pe: "A ko le dẹkun sisọ nipa ohun ti a ti rii ati ti gbọ."
1.213523
10 Kodi simunandikhuthule ngati mkaka
10Ìwọ kò ha ti tú mí dà jáde bí i wàrà,
1.213473
ndipo sindidzakumbukiranso machimo awo."
Ó tún ní, "N kò ní ranti ẹ̀ṣẹ̀ ati ìwà burúkú wọn mọ́.
1.213034
ndipo ndidzawasonkhanitsa kuchokera ku Asiriya.
pẹ̀lú, èmi ó sì ṣà wọn jọ kúrò ni ilẹ̀ Asiria:
1.213005
53 Inu amene munalandira Malamulo amene anaperekedwa ndi angelo ndipo simunawamvere."
53 Ẹ̀yin tí ó gba òfin, gẹ́gẹ́ bí àwọn angẹli ti fi fún ni, tí ẹ kò sì pa á mọ́."
1.21292
Chodziwikiratu nʼchakuti palibe amene amalungamitsidwa pamaso pa Mulungu ndi lamulo, chifukwa, "Wolungama adzakhala ndi moyo mwachikhulupiriro."
Ó dájú pé kò sí ẹnikẹ́ni tí Ọlọrun yóo dá láre nípa òfin, nítorí a kà á pé, "Olódodo yóo wà láàyè nípa igbagbọ.
1.212657
Ndidzakukondani nthawi zonse, Emerson! "
Mo fẹràn rẹ nigbagbogbo, Emerson! "
1.212557
7Chifukwa ndinu thandizo langa,
7 Nítorí ìwọ ni ìrànlọ́wọ́ mi,
1.212556
Iye anachoka, ndipo ankakhala m'nyumba ya bambo ake.
O si lọ kuro, ati ki o joko ni ile baba rẹ.
1.212536
7Chifukwa ndinu thandizo langa,
7Nítorí ìwọ ni ìrànlọ́wọ́ mi,
1.21225
Ine sindikukupatsani monga dziko lapansi limaperekera.
Kì í ṣe bí ayé ti í fúnni ni mo fun yín.
1.211826
4Ngati kutaoneka kuti nʼkoyenera kuti ndipite nawo, adzapita nane limodzi.
Bí ó bá yẹ kí èmi náà lọ, wọn yóo bá mi lọ.
1.211443
Abale samalani, kuti pasapezeke wina aliyense mwa inu wokhala ndi mtima woyipa ndi wosakhulupirira, womulekanitsa ndi Mulungu wamoyo.
Ẹ kíyèsára, ará, kí ó má ṣe sí ẹnikẹ́ni ninu yín tí yóo ní inú burúkú tóbẹ́ẹ̀ ti kò ní ní igbagbọ, tí yóo wá pada kúrò lẹ́yìn Ọlọrun alààyè.
1.211404
Kupereka wanga wonse kwa Tennessee.
Fifun mi gbogbo fun a Tennessee.
1.211256
Casey - Ndikuvomerezana nanu kwathunthu.
Casey - Mo gba pẹlu rẹ patapata.
1.21114
Mkazi wanga ndi mmodzi wa anthu; Sindine.
Iyawo mi jẹ ọkan ninu awọn awon eniyan; Emi kò.
1.210945
Nthaŵi zina ungagwade ndithu, ngati mmene Yesu anachitira.
Nígbà mìíràn o tiẹ̀ lè kúnlẹ̀, gẹ́gẹ́ bí Jésù ti ṣe.
1.21085
Pontho ule anandiphatira basa, anati asimbwe na Baba wanga.
Ẹni tí ó bá kórìíra mi, kórìíra Baba mi.
1.210735
Koma pamene adawadzera (Mtumiki wolonjedzedwayo) ndi zisonyezo zowonekera poyera (kuti iye ndi Mtumiki wa Allah).
Lẹhinna (ami ti o han gbangba) ami iyasọtọ yoo ni fifun ni apapọ.
1.210733
Iwo anauzidwa kuti: "Mitundu yonse ya anthu padziko lapansi adzaona kuti mukutchedwa ndi dzina la Yehova, ndipo adzachita nanu mantha."
10 Gbogbo enia aiye yio si ri pe orukọ OLUWA li a fi npè ọ; nwọn o si ma bẹ̀ru rẹ.
1.210646
Aisraeli Onse Adzapulumuka
Gbogbo Israẹli tòótọ́ ni yóò ní ìgbàlà
1.210606
Lapani ndi kukhulupirira Uthenga Wabwino. "
Ronupiwada ki o si gbagbo ninu Ihinrere. "
1.21048
Yesu anati: "Pa nthawi imeneyo olungama adzawala kwambiri."
Jésù sọ pé: "Ní àkókò yẹn, àwọn olódodo yóò máa tàn yòò."
1.210387
Pakuti mmodzi wa anthu awa ayenera kukhala mboni pamodzi ndi ife zakuuka kwake."
Ó yẹ kí ọ̀kan nínú àwọn wọ̀nyí ṣe ẹlẹ́rìí àjíǹde rẹ̀ pẹ̀lú wa."
1.210326
Ndipo iye anamanga mudzi, namutcha dzina lake ndi dzina la mwana wake, Enoch.
O si kọ ilu kan, o si pe orukọ rẹ̀ ni orukọ ọmọ rẹ̀, Enọku.
1.210096
Pitilizani izi pondikumbukira. "
Ẹ máa ṣe èyí ní ìrántí mi.
1.209897
Inu ndi amene muli ndi mawu amoyo wosatha."
Ìwọ ni ó ni ọ̀rọ̀ ìyè àìnípẹ̀kun.
1.209832
Sipangakhale Yesu m'modzi koma atatu ...
Jesu Kristi kan ko ni le ṣugbọn mẹta ...
1.209818
ndipo ana anuwo afotokozere ana awo,
Ẹ sọ fún àwọn ọmọ yín nípa rẹ̀,kí àwọn náà sọ fún àwọn ọmọ wọn,kí àwọn ọmọ wọn sì sọ fún àwọn ọmọ tiwọn náà.
1.209794
Mwalandilidwa, David & Tsiku Lililonse!
O ṣe itẹwọgba, David & Lojoojumọ!
1.209764
Tsiku lililonse, mlongo wanga anabwera.
Gbogbo ọjọ, arabinrin mi wá.
1.209681
"Kuyamikidwa konse nkwa Allah (Yekha) Muumbi wa thambo ndi nthaka (popanda chofanizira), amene adachita angelo kukhala atumwi eni mapiko, awiriawiri; atatuatatu; ndi anayianayi.
35: 1 iyìn je ti fun Allah, awọn Originator ti awọn ọrun ati aiye, ti o yàn awọn angẹli lati wa ni awon ojise, pẹlu awọn iyẹ, meji, mẹta, ki o si mẹrin.
1.209459
Munthu omwe an'famba, alibe mphanvu yakutsogolera nzayo zace.'
Kì í ṣe ti ènìyàn tí ń rìn àní láti darí àwọn ìṣísẹ̀ ara rẹ̀."
1.20915
Inde aŵa angaiwale, koma Ine sindingaiwale iwe."
Lõtọ, nwọn le gbagbe, ṣugbọn emi kì yio gbagbe rẹ."
1.209128
5 Sudzachita mantha ndi zoopsa za usiku,
5Ìwọ kì yóò bẹ̀rù nítorí ẹ̀rù òru,
1.209025
48 Inu ndinu mboni zazinthu izi.
48 Ẹ̀yin ni ẹlẹ́rìí nǹkan wọnyi.
1.208997
kumunamiza ndi malilime awo;
wọ́n fi ahọ́n wọ́n purọ́ fún un;
1.208804
"Silipezeka tsoka lililonse panthaka (monga chilala) ngakhale pamatupi anu koma lidalembedwa kale m'buku (la Allah) tisadalilenge ndi kulipereka.
"Ko si ọkan ti yio ba ibi lori ilẹ (tabi) ninu ara nyin sugbon o ti wa ni kọ ninu awọn Book (Lawh Mahfūz) ṣaaju ki o to mu A o.
1.208686
Ine ndakumangirani ndithu nyumba yokhalamo Inu, ndiyo malo okhalamo inu nthawi zosatha.
Nisinsinyii mo ti kọ́ ilé kan tí ó lọ́lá fún ọ,níbi tí o óo máa gbé títí lae.
1.208572
Ndachita zimenezi nthawi kapena ziwiri .....
Mo ti ṣe yẹn ni akoko kan tabi meji .....
1.208561
Kodi mwasintha dzina lanu m'mbuyomu?*
Njẹ o ti yi orukọ rẹ pada tẹlẹ?*
1.208502
Kodi Gehena ndi Malo Amene Anthu Ochimwa Amakapsa Kwamuyaya?
Ṣé Ibi Ìdálóró Ayérayé Ni Ọ̀run Àpáàdì?
1.208444
6Pamene wina abwera kudzandiona,
6 Nígbàkígbà tí ẹnìkan bá wá wò mí,
1.208403
ndipo ndidzayenda mʼchoonadi chanu;
èmi ó sì máa rìn nínú òtítọ́ rẹ;
1.208268
Mudzawazindikira ndi zipatso zawo [kapena kuti ntchito zawo]."
Nípa iṣẹ́ ọwọ́ wọn ni ẹ óo fi mọ̀ wọ́n.
1.208242
Big tech: 'tikufuna thandizo lanu'
Imọ -ẹrọ nla: 'A nilo iranlọwọ rẹ'
1.208219
32 Ndipo pamene adamva za kuwuka kwa akufa ena adaseka pwepwete; koma ena adati, Tidzakumvanso iwe za nkhani iyi.
32 Nígbà tí wọ́n gbọ́ pé òkú jinde, àwọn kan ń ṣe yẹ̀yẹ́, àwọn mìíràn ní, "A tún fẹ́ gbọ́ nípa ọ̀rọ̀ yìí nígbà mìíràn."
1.208205
Russian ndi Germany: ndani amapambana?
Russian ati Jẹmánì: tani o ṣẹgun?
1.208193
2 Iye adzaweruza anthu anu mwachilungamo,
2Yóò ṣe ìdájọ́ àwọn ènìyàn rẹ̀ pẹ̀lú òdodo,
1.208088
Taonani, ine ndidzakutumizirani inu Eliya mneneri lisanadze tsiku lalikulu ndi lowopsya la AMBUYE:
N óo rán wolii Elija si yín kí ọjọ́ ńlá OLUWA, tí ó bani lẹ́rù náà tó dé.
1.208042
Pakuti zolakwa zanga ndikuzidziwa bwino, ndipo tchimo langa lili pamaso panga nthawi zonse."
Nitori emi mọ irekọja mi, ẹṣẹ mi si mbẹ niwaju mi nigbagbogbo.
1.207948
Lero, ndakusonkhanitsani m'manja mwa Amayi ...
Loni, Mo ṣajọ ọ sinu awọn iya mi ...
1.207863
"Tandiuza, kodi ndiwe Mroma kodi?"
"Sọ fún mi, wa ni o a Roman?"
1.207843
Tsono uwagawire Aisraeli dziko limeneli kuti likhale cholowa chawo monga momwe ndakulamulira.
Nitorina, jẹ ki ilẹ wọn di apa kan ninu ilẹ-iní Israeli, gẹgẹ bi emi ti paṣẹ fun ọ.
1.207811
Mwana wa Munthu adzabwera mu ulemerero wa Atate wake limodzi ndi angelo ake, ndipo pomwepo mphoto kwa munthu aliyense monga mwa ntchito zake.
Nítorí Ọmọ-Eniyan yóo wá ninu ògo Baba rẹ̀ pẹlu àwọn angẹli rẹ̀, yóo wá fi èrè fún ẹnìkọ̀ọ̀kan gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ rẹ̀.
1.207796
6 Pamene wina abwera kudzandiona,
6 Nígbàkígbà tí ẹnìkan bá wá wò mí,
1.207476
Act 15:9 Ndipo sadalekanitsa ife ndi iwo, nayeretsa mitima yawo m'chikhulupiriro.
15:9 Ati pe ko ṣe iyatọ ohunkohun laarin awa ati wọn, wẹ ọkàn wọn di mimọ nipa igbagbọ.
1.207257
Nʼchifukwa chake anthu amati, "Kodi Sauli alinso mmodzi wa aneneri?"
Nitori eyi, o ni tan-sinu a owe, "Ṣe Saulu tun jẹ ninu awọn woli?"
1.207192
"Ndipo tikadafuna tikadakuonetsa iwo (amene akuchitira kaduka Chisilamu) ndipo ukadawadziwa ndi zizindikiro zawo.
Àti pé tí A bá fẹ́ Àwa ìbá fi wọ́n hàn ọ́, ìwọ ìbá sì mọ̀ wọ́n pẹ̀lú àmì wọn.
1.207121
Mmene Gayo Anathandizila Abale Ake
Bí Gáyọ́sì Ṣe Ran Àwọn Ará Lọ́wọ́
1.206989
5 Sudzachita mantha ndi zoopsa za usiku,
5 Ìwọ kì yóò bẹ̀rù nítorí ẹ̀rù òru,
1.206818
Kodi chilengedwe sichimakuphunzitsani kuti ngati mwamuna ali ndi tsitsi lalitali, ndi chamanyazi kwa iye, koma kuti ngati mkazi ali ndi tsitsi lalitali, ndi ulemerero wake?
14 Ani ẹda tikararẹ̀ kò ha kọ́ nyin pe, bi ọkunrin ba ni irun gigun, àbuku ni fun u?
1.206682
komatu monga Iye wakuitana inu ali woyera mtima, khalani inunso oyera mtima m'makhalidwe anu onse;
Ṣugbọn gẹ́gẹ́ bí ẹni tí ó pè yín ti jẹ́ mímọ́, bẹ́ẹ̀ ni kí ẹ̀yin náà jẹ́ mímọ́ ninu gbogbo ìwà yín.
1.206679
"Ndipo amene sakhulupirira Allah ndi Mtumiki Wake, ndithu Ife tawakonzera okanira chilango cha Moto woyaka.
" Ati pe ẹnikẹni ti kò ba gba Ọlọhun gbọ ati Ojisẹ Rẹ, dajudaju Awa pese ina elejo fofo silẹ fun awọn alaigbagbọ " [Suuratul-Fath: 13].
1.206615
Pakuti zonsezi nza kwa inu, kuti chisomocho, chochulukitsidwa mwa unyinjiwo, chichulukitsire chiyamiko ku ulemerero wa Mulungu.
Nítorí tiyín ni gbogbo èyí, kí oore-ọ̀fẹ́ lè máa pọ̀ sí i fún ọpọlọpọ eniyan, kí ọpẹ́ yín lè máa pọ̀ sí i fún ògo Ọlọrun.
1.206586
8"Kodi ndingakusiye bwanji iwe Efereimu?
8"Báwo ni èmi ó ṣe fi ọ́ sílẹ̀, Efraimu?
1.20643
Ndipo adawayitana iwo mayina yemweyo amene atate wake anali wotchedwa pamaso.
Ati pe o pe wọn pẹlu awọn orukọ kanna ti baba rẹ ti pe wọn tẹlẹ.
1.206337
Koma Atate wanu wakumwamba amazidyetsa.
Sibẹ Baba yín tí ń bẹ ní ọ̀run ń bọ́ wọn.
1.206286
24Munthu wosauka ine; adzandilanditsa ndani m'thupi la imfa iyi?
24 Emi ẹni òṣi! tani yio gbà mi lọwọ ara ikú yi?
1.206233
19"Ndinayitana abwenzi anga
19"Mo pe àwọn ọ̀rẹ́ mi