score
float32 1.04
1.25
| Tsonga
stringlengths 10
497
| Yoruba
stringlengths 9
500
|
|---|---|---|
1.249248
|
A xi nge hi tshiki ku fana ni nuna wa mina."
|
Kò sì ní pa wá tì láé bí ọkọ mi ṣe pa wá tì."
|
1.249167
|
Naswona n'wina mi basile, kambe ku nga ri hinkwenu."
|
Ẹ̀yin mọ́, ṣugbọn kì í ṣe gbogbo yín."
|
1.248577
|
Wena wa ha veke vhinyo leyinene ku fikela sweswi."
|
Iwọ ti pa ọti-waini rere titi di isisiyi! "
|
1.245466
|
Va ta avanyisiwa hi ku avanyisa loku tlurisaka!"
|
Wọnyi ni yio si gba awọn siwaju sii sanlalu idajọ. "
|
1.244357
|
Hi siye swilo hinkwaswo naswona ha ku landzela."
|
Àwa ti fi ohun gbogbo tí a ní sílẹ̀, a sì ti ń tẹ̀lé ọ.
|
1.243866
|
ndzi endlile leswo biha emahlweni ka wena;
|
ni mo sì ṣe búburú níwájú rẹ̀,
|
1.243006
|
Mubebwa-nga-muthu u khou ḓa e kha vhugala ha Khotsi awe e na vharuṅwa vhawe; ndi hone a tshi ḓo ṋea muṅwe na muṅwe nga he a shuma ngaho.
|
27 Nitori Ọmọ-enia yio wá ninu ogo Baba rẹ̀ pẹlu awọn angẹli rẹ̀; nigbana ni yio san a fun olukuluku gẹgẹ bi iṣẹ rẹ̀.
|
1.242792
|
"Musi Mubebwa-nga-muthu a tshi vhuya e vhugalani hawe e na vharuṅwa vhoṱhe, ndi hone a tshi ḓo dzula kha khuluṋoni yawe ya vhugala.
|
"Nígbà tí Ọmọ-Eniyan bá yọ ninu ìgúnwà rẹ̀ pẹlu gbogbo àwọn angẹli, nígbà náà ni yóo jókòó lórí ìtẹ́ ògo rẹ̀.
|
1.242464
|
Ndi hone a tshi ḓo khethekanya vhathu sa mulisa a tshi khethekanya nngu na mbudzi.
|
On o si yà wọn lati ọkan miiran, gẹgẹ bi oluṣọ ya awọn agutan lati ewúrẹ.
|
1.242167
|
Naswona swiphemu swa xona hinkwaswo swi tsariwe ebukwini ya wena,
|
Gbogbo wọn ni a kọ orúkọ wọn sinu ìwé.
|
1.241442
|
Ngavhe U pfe ndi tshi U laya, ndi misi mulalo wau u tshi nga mulambo; zwivhuya zwau ndi misi zwi tshi nga magabelo a lwanzhe."
|
Nígbà náà, àlàáfíà rẹ ì bá dà bí odò, òdodo rẹ ì bá sì dà bí ìgbì òkun."
|
1.240372
|
Muporofita wa Yuda a songo bulwaho dzina o kundelwa u ita mini, nahone ho vha na mvelelo dzifhio?
|
Kí ni wòlíì tó wá láti Júdà yẹn kò ṣe, kí ló sì yọrí sí?
|
1.239754
|
vha vhidzelela Loto vha ri, "Vhaḽa vhanna vhe vha u dalela madekwana ano vha ngafhi?
|
Wọ́n pe Lọti, wọ́n ní, "Níbo ni àwọn ọkunrin tí wọ́n dé sọ́dọ̀ rẹ ní alẹ́ yìí wà?
|
1.239426
|
Kutani hina hi ri twile rito leri, loko ri huma etilweni, hikuva a hi ri na yena entshaveni yo hlawuleka.
|
Àwa fúnra wa gbọ́ ohùn yìí nígbà tí ó wá láti ọ̀run nítorí a wà pẹlu rẹ̀ lórí òkè mímọ́ nígbà náà.
|
1.239264
|
Kutani ndzi nga byi endlisa ku yini vubihi lebyi lebyikulu ndzi dyohela Xikwembu+ hakunene?"
|
Báwo ni mo ṣe lè ṣe ibi yìí, kí n sì dẹ́ṣẹ̀ sí Ọlọrun mi?"
|
1.238315
|
"Musi wazwo a ni tsha ḓo vhuya na mmbudzisa na tshithu.
|
"Ní ọjọ́ náà, ẹ kò ní bi mí léèrè ohunkohun.
|
1.237987
|
Hikwalaho Muxe a heta ntirho.
|
Bẹ́ẹ̀ ni Mose ṣe parí gbogbo iṣẹ́ náà.
|
1.237086
|
ndzi vitanile n'wananga a huma Egipta.
|
mo sì pe ọmọ mi jáde láti Ejibiti wá.
|
1.237043
|
Ndi hone vha tshi dzula henefho mavuni nae, vha fhedza maḓuvha maṱanu na mavhili na vhusiku hao vha sa vhuyi vha amba tshithu nae, nge vha vhona a tshi khou tambula zwihulu.
|
Wọ́n jókòó ní ilẹ̀ẹ́lẹ̀ pẹlu rẹ̀ fún ọjọ́ meje, tọ̀sán-tòru, láìsọ nǹkankan, nítorí pé wọ́n rí i bí ìrora náà ti pọ̀ tó.
|
1.236934
|
Mubebwa-nga-muthu u khou ḓa e kha vhugala ha Khotsi awe e na vharuṅwa vhawe; ndi hone a tshi ḓo ṋea muṅwe na muṅwe nga he a shuma ngaho.
|
Nítorí Ọmọ-Eniyan yóo wá ninu ògo Baba rẹ̀ pẹlu àwọn angẹli rẹ̀, yóo wá fi èrè fún ẹnìkọ̀ọ̀kan gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ rẹ̀.
|
1.236721
|
xana a hi xona xi nga Tata wa n'wina, yena loyi a mi vumbeke ke?
|
Ǹjẹ́ òun kọ́ ni baba yín, Ẹlẹ́dàá yín,
|
1.234549
|
Vanhu va matiko hinkwawo lawa ya mi rhendzeleke, va ta vona leswi mina HOSI ndzi tirhaka swona, hikuva leswi ndzi nga ta mi endlela swona, swi ta chavisa ngopfu.
|
Gbogbo àwọn eniyan tí ẹ̀ ń gbé ààrin wọn yóo sì rí iṣẹ́ OLUWA, nítorí ohun tí n óo ṣe fún wọn yóo bani lẹ́rù jọjọ.
|
1.234489
|
Tshamani mi ri karhi mi endla leswi leswaku mi ndzi tsundzuka."
|
Ẹ máa ṣe èyí ní ìrántí mi.
|
1.233706
|
U tlule ntwanano wa mina."
|
Nitoriti o ti sọ majẹmu mi di ofo. "
|
1.233079
|
Fhedzi Maria na Yosefa vho vha vha tshe vho ḓaḓa.
|
Maria ati Joseph won gan ni iyawo ni niwaju Ọlọrun.
|
1.232813
|
Xana ndzi murindzi+ wa makwerhu?"
|
Ṣe Mo jẹ olutọju arakunrin mi?"
|
1.231818
|
Ndi hone vha tshi ṱuwa vha dzhena tshikepeni; hone vha si vhuye vha fasha na khovhe na nthihi vhusiku honoho.
|
Wọ́n jáde, wọ́n sì wọ inú ọkọ̀ ojú omi; ní òru náà wọn kò sì mú ohunkóhun.
|
1.231762
|
Hikwalaho a ku eka Labani: "I yini leswi u ndzi endleke swona?
|
Ó sì wí fún Labani pé, "Èwo ni ìwọ ṣe sí mi yìí?
|
1.231586
|
Va rindze ku hetiseka ka xitshembiso xa Xikwembu malunghana ni misava leyintshwa.
|
Fun gbogbo ileri lati ọdọ Ọlọrun ipin kan wa.
|
1.231382
|
ma suka eka rixaka rin'wana ma tlulela eka rin'wana,
|
tí wọn ń lọ káàkiri láti orílẹ̀-èdè kan dé ekeji,láti ìjọba kan sí òmíràn,
|
1.231354
|
Loko u ya eximatsini, ndzi ta ya exineneni; kambe loko u ya exineneni, ndzi ta ya eximatsini."+
|
Bí o bá lọ sí apá òsì, èmi á lọ sí apá ọ̀tún, bí o bá sì lọ sí apá ọ̀tún, èmi á lọ sí apá òsì.
|
1.231096
|
[27:45] We fanele hambisa kuze Thamoud bo fo Saaleh tshela You khonza
|
thambs òàì äîëæåí áûòü çâóê áüþùåãîñÿ ñòåêëà à îí íå áóäåò ðåàãèðîâàòü.
|
1.230727
|
39 Hi ku vone rini u vabya kumbe u ri ekhotsweni kutani hi ta eka wena?'
|
39 Tabi nigbawo li awa ri ti iwọ ṣe aisan, ti a bojuto ọ? tabi ti iwọ wà ninu tubu, ti awa si tọ̀ ọ wá?
|
1.230662
|
Kambe a tshembaka rifuwo+ rakwe ro tala,
|
bí kò ṣe ni ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọrọ̀ rẹ̀ ni ó gbẹ́kẹ̀lé,
|
1.22918
|
Musi ni tshi guda nga ha Mudzimu, ni ḓo mu funa nga ho engedzeaho.
|
Bí ìmọ̀ tó o ní nípa Jèhófà ti ń pọ̀ sí i, bẹ́ẹ̀ ni ìfẹ́ tó o ní fún un yóò máa jinlẹ̀ sí i.
|
1.228463
|
4Ri ni ṅwalela hezwi uri ri takale tshoṱhe.
|
À ń kọ àwọn nǹkan wọnyi si yín kí ayọ̀ wa lè kún.
|
1.227696
|
Ene we a si tshivhe na Murwa wawe muthihi fhedzi, a tou mu kovha a tshi ri a fele roṱhe; a tshi ri ṋea Murwa wawe ndi zwine a nga kundwa ngani u ri ṋea zwoṱhe-zwoṱhe naa?
|
32 Ẹniti kò da Ọmọ on tikararẹ̀ si, ṣugbọn ti o jọwọ rẹ̀ lọwọ fun gbogbo wa, yio ha ti ṣe ti kì yio fun wa li ohun gbogbo pẹlu rẹ̀ lọfẹ?
|
1.227638
|
36 Munhu yoloye a hlamula a ku: "Kutani i mani, nkulukumba, leswaku ndzi ta pfumela eka yena?"
|
36 On si dahùn wipe, Tani, Oluwa, ki emi ki o le gbà a gbọ́?
|
1.227336
|
A ni zwi ḓivhi uri ndi na maanḓa a u ni vhofholola na a u ni vhamba kha tshifhambano naa?"
|
O kò mọ̀ pé mo ní àṣẹ láti dá ọ sílẹ̀, mo sì ní àṣẹ láti kàn ọ́ mọ́ agbelebu?
|
1.227182
|
Vhane vha ofha Muṋe washu vha tshi amba nga tshavho,
|
Ṣugbọn awọn ti o bẹru Oluwa wọn,
|
1.226488
|
Hikuva mitirho ya yena a yi ri leyo biha; kasi ya makwavo a yi lulamile.
|
Nítorí iṣẹ́ tirẹ̀ burú, ṣugbọn ti arakunrin rẹ̀ dára.
|
1.226047
|
Va khongele eka Xikwembu ku nga ri eka Yesu.
|
Ọlọ́run ni wọ́n gbàdúrà sí, kì í ṣe Jésù.
|
1.224794
|
Kutani a ku eka vona: "Xana xifaniso ni marito lawa i swa mani?"
|
Ó wá bi wọ́n pé, "Àwòrán ati àkọlé ta ni èyí?
|
1.224467
|
"N'wina Mi Fanele Ku Velekiwa Ra Vumbirhi"
|
"Ìwọ́ gbọ́dọ̀ di àtúnbí"
|
1.224337
|
Ndi zwiné vhathu vhoṱhe vha ḓo ḓivha ngazwo' zwauri ni vhafunziwa vhanga arali u funana hu hone kha inwi."
|
Èyí ni yóo jẹ́ kí gbogbo eniyan mọ̀ pé ọmọ-ẹ̀yìn mi ni yín, bí ẹ bá fẹ́ràn ara yín.
|
1.224327
|
"Mi xaviwile hi nxavo.
|
Iyebíye ni Ọlọrun rà yín.
|
1.224176
|
Ha Yini Vatswari Va Mina Va Nga Lavi Leswaku Ndzi Tiphina?
|
Kí Nìdí Tí Àwọn Òbí Mi Ò Fẹ́ Kí N Gbádùn Ara Mi Rárá?
|
1.223708
|
Zwino arali na tou vhofhololwa nga Murwa, ndi hone ni tshi ḓo vha no vhofhololwa vhukuma.
|
Nítorí náà, bí Ọmọ bá sọ yín di òmìnira, ẹ óo di òmìnira nítòótọ́.
|
1.223408
|
ú ta vona vatukulu va yena, a hanya malembe layo tala;
|
ọ̀rọ̀ tí ó pàṣẹ, fún ẹgbẹgbẹ̀rún ìran,
|
1.222804
|
Xana Mi Tshemba Leswaku Hi N'wina Ntsena Lava Nga Ta Ponisiwa?
|
Ṣé Ẹ Rò Pé Ẹ̀yin Nìkan Ló Máa Rí Ìgbàlà?
|
1.222742
|
41 N'wana wa munhu u ta rhuma tintsumi takwe, kutani emfun'weni wakwe ti ta humesa swilo hinkwaswo leswi khunguvanyisaka+ ni vanhu lava endlaka swiendlo swo kala nawu,
|
41Ọmọ Ènìyàn yóò ran àwọn angẹli rẹ̀, wọn yóò sì kó gbogbo ohun tó ń mú ni dẹ́ṣẹ̀ kúrò ní ìjọba rẹ̀ àti gbogbo ènìyàn búburú.
|
1.222463
|
U ta vona swilo leswikulu ku tlula leswi."
|
Í si kuwolu je mennu barako xa bun ɲinnu ti."
|
1.222114
|
a vhulaha mahosi a maanḓa;
|
tí ó sì pa àwọn alágbára ọba.
|
1.22198
|
U na mashudu ane a sa khukhulisee nga Nṋe."
|
Ẹni tí kò bá ṣiyèméjì nípa mi ṣe oríire!
|
1.221451
|
Xana a ndzi nga tirheli Rahele eka wena?
|
Emi kò sìn ọ fun Rakeli?
|
1.22057
|
Mudzimu a mu nea vharwa vha sumbe (7) na vhananyana vhararu vha u naka.
|
Ó tún bí ọmọkunrin meje ati ọmọbinrin mẹta.
|
1.220117
|
Mudzimu a mu vhudza a ri, "Iwe u pfi Jakopo, hone a u tsha ḓo pfi Jakopo, u vho ḓo pfi Israele."
|
Ọlọrun wí fún un pé, "Jakọbu ni orúkọ rẹ, ṣugbọn wọn kò ní pè ọ́ ní Jakọbu mọ́, Israẹli ni orúkọ rẹ yóo máa jẹ́.
|
1.219927
|
Ha Yini Ndzi Nga Ri Na Vanghana?
|
Kí Nìdí Tí Mi Ò Fi Ní Ọ̀rẹ́ Kankan?
|
1.219722
|
vha vhidzelela Loto vha ri, "Vhaḽa vhanna vhe vha u dalela madekwana ano vha ngafhi?
|
19:5 Nwọn si pè Loti jade lati, nwọn si wi fun u: "Nibo li awọn ọkunrin ti o wọ si nyin li oru?
|
1.219525
|
Vha nga fulufhela hani ane vha sa athu pfa a tshi ambiwa?
|
Bawo ni wọn ṣe gbagbọ ninu wọn ti wọn ko ba ti gbọ alaye rẹ ni kikun?
|
1.21949
|
A wu swi tivi xana leswaku ndzi ni matimba ya ku ku ntshunxa, ni matimba ya ku ku vamba ke?"
|
O kò mọ̀ pé mo ní àṣẹ láti dá ọ sílẹ̀, mo sì ní àṣẹ láti kàn ọ́ mọ́ agbelebu?
|
1.219468
|
N'wina ma n'wi tiva, hikuva ú tshama na n'wina, naswona ú le ndzeni ka n'wina.
|
Ṣugbọn ẹ̀yin mọ̀ ọ́n, nítorí ó ń ba yín gbé, ó sì wà ninu yín.
|
1.219426
|
Farisanani nga u angulana mihwalo, ngauralo hu ḓo vha u khunyeledza mulayo wa Khristo.
|
Ẹ ru ẹrù ọmọnikeji nyin, ati nitorinaa mu ofin Kristi ṣẹ.
|
1.219418
|
Sweswi ndza swi tiva leswaku u ni ripfumelo eka mina hikuva a wu ndzi alelanga hi n'wana wa wena loyi a nga swakwe.'
|
Nísinsin yìí ni mo mọ̀ pé o bẹ̀rù Ọlọ́run, nítorí pé ìwọ kò fi ọmọ rẹ, àní, ọmọ rẹ kan ṣoṣo dù mí."
|
1.219304
|
Xana a ndzi nga tirheli Rahele eka wena?
|
Ṣebí nítorí Rakẹli ni mo fi sìn ọ́?
|
1.219226
|
U vutisile a ku: "Kahle-kahle i mani hlonga ro tshembeka ni ro tlhariha?"
|
Ó béèrè pé: "Ní ti tòótọ́, ta ni ẹrú olóòótọ́ àti olóye?"
|
1.219167
|
Madzina avho nga a thuthwe buguni ya vha tshilaho!
|
O si kọ orukọ wọn ninu iwe ti aye.
|
1.218939
|
"Hambileswi mi nga si tshamaka mi n'wi vona, ma n'wi rhandza.
|
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ẹ kò rí i, sibẹ ẹ fẹ́ràn rẹ̀.
|
1.21823
|
Ndlela Leyi Gayo A Pfuneke Vamakwavo Ha Yona
|
Bí Gáyọ́sì Ṣe Ran Àwọn Ará Lọ́wọ́
|
1.218118
|
20Ndi hone Yesu a tshi thoma u teketela miḓi ye a shuma khayo vhunzhi ha maḓembe awe, a i teketelela u sa laṱa vhuvhi hayo a ri, 21
|
Nígbà náà ni Jesu bẹ̀rẹ̀ sí bá àwọn ìlú wọ̀n-ọn-nì wí níbi tí ó ti ṣe àwọn iṣẹ́ ìyanu pupọ jùlọ, nítorí wọn kò ronupiwada.
|
1.217857
|
Tiva leswaku u'nwana na un'wana loyi a tirhaka hi mukhuva lowu,ita hakeriwa hi Hosi,ku nga va hlonga kumbe loyi a tirhelaka male.
|
Nítorí ẹ mọ̀ pé ohun rere tí ẹnìkọ̀ọ̀kan yín bá ṣe, olúwarẹ̀ ìbáà jẹ́ ẹrú tabi kí ó jẹ́ òmìnira, yóo rí èrè gbà lọ́dọ̀ Oluwa.
|
1.217852
|
Hikuva nwana wa munhu u tile ku ta lava no ponisa leswi lahlekeke."
|
Nítoí Ọmọ-Eniyan dé láti wá àwọn tí wọ́n sọnù kiri, ati láti gbà wọ́n là.
|
1.217816
|
Vhaḽa vharuṅwa vhavhili vha swika Sodoma nga madekwana, vha wana Loto o dzula khoroni ya muḓi.
|
1AWỌN Angeli meji si wá si Sodomu li aṣalẹ; Loti si joko li ẹnu-bode Sodomu: bi Loti si ti ri wọn, o dide lati pade wọn: o si dojubolẹ;
|
1.217804
|
Xana a ndzi nga tirheli Rahele eka wena?
|
Ṣe Mo ko sin ọ fun Rakeli?
|
1.217508
|
Vhane vha ṱoḓa tshiga ndi vhathu vhavhi vho furalelaho Mudzimu; a vha nga itelwi tshiga arali tshi si tsha Jonasi."
|
Ìran burúkú ati oníbọkúbọ ń wá àmì; ṣugbọn a kò ní fi àmì kan fún un, àfi àmì Jona.
|
1.217422
|
Vha hashu, musi ni tshi lingiwa nga nḓila nnzhi ni vhone e mashudu fhedzi; 3
|
Ẹ̀yin ará mi, ẹ kà á sí ayọ̀ gidi nígbà tí oríṣìíríṣìí ìdánwò bá dé ba yín.
|
1.217419
|
"U Tsakise Xikwembu Swinene"
|
"Ó Ti Wu Ọlọ́run Dáadáa"
|
1.21725
|
Kutani Xikwembu xi ta sula mihloti hinkwayo ematihlweni ya vona."
|
'Ọlọ́run yóò sì nu omijé gbogbo nù kúrò ni ojú wọn.' "
|
1.216905
|
Ndzi ta famba entiyisweni wa wena.
|
èmi ó sì máa rìn nínú òtítọ́ rẹ;
|
1.216877
|
Ndzi rhuma murhumiwa wa mina emahlweni ka wena, la nga ta ku lunghiselela ndlela;) +
|
Mo rán oníṣẹ́ mi ṣiwaju rẹ òun ni yóo palẹ̀ mọ́ dè ọ́.
|
1.216684
|
Hikuva masiku ya vanhu va mina ma ta fana ni masiku ya murhi; ni ntirho wa mavoko ya vona, vahlawuriwa va mina va ta wu tirhisa hi xitalo."
|
Àwọn eniyan mi yóo pẹ́ láyé bí igi ìrókò,àwọn àyànfẹ́ mi yóo sì jèrè iṣẹ́ ọwọ́ wọn.
|
1.216556
|
Arali a mmbulaha, ri ḓo vha phuli dzanu.
|
Bí ó bá pa mí, a óo di ẹrú yín.
|
1.216448
|
"Hlawulani namuntlha loyi mi nga ta n'wi tirhela." - YOX.
|
"Ẹ yan ẹni tí ẹ̀yin yóò máa sìn fún ara yín." - JÓṢ.
|
1.216315
|
U te: 'Xana u nga tsakela ku famba na mina na Silasi?
|
Ó ń béèrè pé: 'Ṣé wàá fẹ́ láti tẹ̀ lé èmi àti Sílà?
|
1.216196
|
Hikokwalaho, loko mina, hambileswi ndzi nga Hosi ni Mudyondzisi, ndzi mi hlambise milenge, na n'wina mi fanele ku hlambisana milenge.
|
Bí èmi Oluwa ati Olùkọ́ni yín bá fọ ẹsẹ̀ yín, ó yẹ kí ẹ máa fọ ẹsẹ̀ ẹnìkejì yín.
|
1.216114
|
I yini leswi endlekeke eka vana va Adamu?
|
Kí ló ṣẹlẹ̀ sí àwa àtọmọdọ́mọ Ádámù?
|
1.215951
|
7 A ku eka vona: "A hi swa n'wina ku tiva minkarhi kumbe tinguva+ leswi Tatana a swi vekeke hi vulawuri+ byakwe;
|
Ó dá wọn lóhùn pé, "Kì í ṣe tiyín láti mọ àkókò tabi ìgbà tí Baba ti fi sí ìkáwọ́ ara rẹ̀ nìkan ṣoṣo.
|
1.215898
|
niloko mi aka xisaka xa n'wina exikarhi ka tinyeleti,
|
bí ìwọ tilẹ̀ tẹ́ ìtẹ́ rẹ sí àárín àwọn ìràwọ̀,
|
1.215792
|
12 n'wina a ma ha n'wi pfumeleli ku endlela tata wakwe kumbe mana+ wakwe nchumu wo karhi,
|
Bẹ́ẹ̀ ni ẹ̀yin kò si jẹ́ kí ó ṣe ohunkóhun fún baba tàbí iyá rẹ̀ mọ́.
|
1.215283
|
Hangwa vha hau na nnḓu ya khotsi au.
|
Ati gbagbe awọn eniyan rẹ ati ile baba rẹ.
|
1.215258
|
"Swi Hi Khumbile Ku Vona Rirhandzu Ro Tano"
|
"Irú Ìfẹ́ Yìí Wú Wa Lórí Gan-an Ni"
|
1.215217
|
Vhane vha mpfulufhela vha ḓo vha na maḓembe haya: Vha ḓo pandela thuṅwa dza Saṱhane nga dzina ḽanga; vha ḓo amba nga nyambo dzisili; 18
|
[17]Àmi wọnyi ni yio si ma ba awọn ti o gbagbọ́ lọ; Li orukọ mi ni nwọn o ma lé awọn ẹmi èṣu jade; nwọn o si ma fi ède titun sọ̀rọ;
|
1.215164
|
48 Kutani Labani a ku: "Nhulu leyi i mbhoni exikarhi ka mina na wena namuntlha."
|
48Labani sì wí pé, "Òkìtì yìí jẹ́ ẹ̀rí láàrín èmi àti ìwọ ní òní."
|
1.214493
|
Naho zwo ralo, a hu na na tshithihi tshazwo tshine tsha ḓo wela fhasi Khotsi aṋu a sa zwi ḓivhi.
|
Ati ki o sibẹsibẹ ko ọkan ninu wọn ti yio ṣubu si ilẹ lai rẹ Baba.
|
1.214402
|
DECEMBER 2013 Xana Ha Wu Lava Mpfuno Wa Xikwembu?
|
DECEMBER 2013 Ǹjẹ́ A Nílò Ọlọ́run?
|
1.214355
|
Xana vamakwavo va xisati a va kona kwala eka hina-ke?"
|
Awọn arabinrin rẹ kò tun nihin pẹlu wa?"Nwọn si kó nla ẹṣẹ ni i.
|
1.213877
|
Rhwalelanani mindzhwalo, kutani, hi ku endlisa sweswo, mi ta va mi hetisa nawu wa Kriste.
|
Ẹ ru ẹrù ọmọnikeji nyin, ati nitorinaa mu ofin Kristi ṣẹ.
|
1.213605
|
Xikwembu i mbhoni exikarhi ka mina na wena."+
|
Ẹ̀rí ni wọ́n fi ṣe láàrin àwa pẹlu yín.
|
1.213546
|
ú ta faya tinhloko ta Vamowabu,
|
Yóò tẹ̀ fọ́ orí Moabu,
|
1.21312
|
8 Ina, hi mina Yohane la tweke ni ku vona swilo leswi.
|
8 Emi Johanu li ẹniti o gbọ́ ti o si ri nkan wọnyi.
|
Tsonga-Yoruba_Sentence-Pairs Dataset
This dataset contains sentence pairs for African languages along with similarity scores. It can be used for machine translation, sentence alignment, or other natural language processing tasks.
This dataset is based on the NLLBv1 dataset, published on OPUS under an open-source initiative led by META. You can find more information here: OPUS - NLLB-v1
Metadata
- File Name: Tsonga-Yoruba_Sentence-Pairs
- Number of Rows: 187996
- Number of Columns: 3
- Columns: score, Tsonga, Yoruba
Dataset Description
The dataset contains sentence pairs in African languages with an associated similarity score. Each row consists of three columns:
score: The similarity score between the two sentences (range from 0 to 1).Tsonga: The first sentence in the pair (language 1).Yoruba: The second sentence in the pair (language 2).
This dataset is intended for use in training and evaluating machine learning models for tasks like translation, sentence similarity, and cross-lingual transfer learning.
References
Below are papers related to how the data was collected and used in various multilingual and cross-lingual applications:
[1] Holger Schwenk and Matthijs Douze, Learning Joint Multilingual Sentence Representations with Neural Machine Translation, ACL workshop on Representation Learning for NLP, 2017
[2] Holger Schwenk and Xian Li, A Corpus for Multilingual Document Classification in Eight Languages, LREC, pages 3548-3551, 2018.
[3] Holger Schwenk, Filtering and Mining Parallel Data in a Joint Multilingual Space ACL, July 2018
[4] Alexis Conneau, Guillaume Lample, Ruty Rinott, Adina Williams, Samuel R. Bowman, Holger Schwenk and Veselin Stoyanov, XNLI: Cross-lingual Sentence Understanding through Inference, EMNLP, 2018.
[5] Mikel Artetxe and Holger Schwenk, Margin-based Parallel Corpus Mining with Multilingual Sentence Embeddings arXiv, Nov 3 2018.
[6] Mikel Artetxe and Holger Schwenk, Massively Multilingual Sentence Embeddings for Zero-Shot Cross-Lingual Transfer and Beyond arXiv, Dec 26 2018.
[7] Holger Schwenk, Vishrav Chaudhary, Shuo Sun, Hongyu Gong and Paco Guzman, WikiMatrix: Mining 135M Parallel Sentences in 1620 Language Pairs from Wikipedia arXiv, July 11 2019.
[8] Holger Schwenk, Guillaume Wenzek, Sergey Edunov, Edouard Grave and Armand Joulin CCMatrix: Mining Billions of High-Quality Parallel Sentences on the WEB
[9] Paul-Ambroise Duquenne, Hongyu Gong, Holger Schwenk, Multimodal and Multilingual Embeddings for Large-Scale Speech Mining, NeurIPS 2021, pages 15748-15761.
[10] Kevin Heffernan, Onur Celebi, and Holger Schwenk, Bitext Mining Using Distilled Sentence Representations for Low-Resource Languages
- Downloads last month
- 12