Dataset Viewer
Auto-converted to Parquet
score
float32
1.04
1.25
Ewe
stringlengths
10
494
Yoruba
stringlengths
9
499
1.249462
6 Yayrawo ava ame dzɔdzɔe ƒe ta dzi,
6 Ìbùkún wà ní orí olódodo:
1.248488
12 Eɖo eŋu nɛ be: "Alo menye nya si Afetɔ de nu nam lae wòle be magblɔ oa?"
12 Ó sì dáhùn wí pé, "Ṣé kí n má sọ nǹkan tí Olúwa fi sí mi lẹ́nu?"
1.247445
17 Afi sia wokpee le hesubɔe, ke wo dometɔ aɖewo meka ɖe
17 Nigbati nwọn si ri i, nwọn foribalẹ fun u: ṣugbọn awọn miran ṣiyemeji.
1.247398
Gake Yesu anye fia yi ɖe mavɔmavɔ me, eye eƒe fiaɖuƒe nu mayi gbeɖe o!'
Yóo jọba lórí ìdílé Jakọbu títí lae, ìjọba rẹ̀ kò ní lópin.
1.247192
Elabena aʋatsoɖasefowo tso ɖe ŋunye,
nítorí àwọn ẹlẹ́rìí èké ti dìde sí mi,
1.246839
Elabena míawo ŋutɔwo míesee tso eya ŋutɔ ƒe nu me."
Nitori awa ti gbọ ara wa, lati ara rẹ ẹnu. "
1.246109
Oo Yordan, nu ka tae nègbugbɔ ɖe megbe?
Ìwọ Jordani, tí ìwọ fi padà sẹ́yìn?
1.245026
Ke aleke woaɖe gbeƒã, ne womedɔ wo ɖa hafi o mahã?
Báwo ni àwọn kan yóo ṣe lọ kéde rẹ̀ láìjẹ́ pé a bá rán wọn lọ?
1.244201
nuxaxa geɖe ava anyigba sia dzi eye Mawu ƒe dɔmedzoe ava dukɔ sia dzi.
Nitori ipọnju nla yio wà lori ilẹ na ati ibinu nla lori awọn eniyan yii.
1.24412
Eye woaƒo dukɔwo katã nu ƒu ɖe eŋkume, eye wòama amewo me tso wo nɔewo gbɔ, abe ale si alẽkplɔla maa alẽwo tso gbɔ̃wo gbɔe ene.
Gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè yóo péjọ níwájú rẹ̀, yóo wá yà wọ́n sọ́tọ̀ọ̀tọ̀, bí olùṣọ́-aguntan tíí ya àwọn aguntan sọ́tọ̀ kúrò lára àwọn ewúrẹ́.
1.243823
, Ro 11:33 Mawu ƒe kesinɔnuwo kple nunya g.
11:33 oh, awọn ogbun ti awọn lóęràá ti awọn ọgbọn ati ìmọ Ọlọrun!
1.243743
"Mava du sia me o,
"Òun kì yóò wọ ìlú yìí wá
1.243493
Elabena míekpɔ eƒe ɣletivi esime míenɔ ɣedzeƒe, eye míeva be míade bubu eŋu.'"
Àwa ti rí ìràwọ̀ rẹ̀ ní ìlà-oòrùn, a sì wá láti foríbalẹ̀ fún un."
1.243123
Etsɔ la, miho ɖe wo ŋu, eye Afetɔ anɔ kpli mi.'"
Ọla ki iwọ ki o si jade lọ si wọn, ati Oluwa yio si pẹlu nyin. "
1.242412
Egblɔ be: "Miawo la migana woayɔ mi be Rabi o, elabena ame ɖeka koe nye miaƒe nufiala, eye mi katã la nɔviwo mienye.
Ṣugbọn ẹ̀yin ní tiyín, ẹ má jẹ́ kí wọ́n pè yín ní 'Olùkọ́ni,' nítorí ẹnìkan ṣoṣo ni olùkọ́ni yín; arakunrin ni gbogbo yín jẹ́.
1.242109
7 Meɖea ŋku ɖa le ame dzɔdzɔewo ŋu o;
7Òun kì í mú ojú rẹ̀ kúrò lára olódodo,
1.241871
Yesu gblɔ be: "Vi eve le ŋutsu aɖe si.
Jesu ní, "Ọkunrin kan ní ọmọ meji.
1.241765
Elabena amesi le didim be, yealɔ̃ agbe, eye yeakpɔ ŋkeke nyuiwo la, nekpɔ eƒe aɖe dzi ɖe vɔ̃ ŋu kple eƒe nuyiwo dzi, bene woagagblɔ alakpanya o;
Nítorí ó wà ní àkọsílẹ̀ pé,"Ẹni tí ó bá fẹ́ ìgbé-ayé tí ó wù ú,tí ó fẹ́ rí ọjọ́ tí ó dára,ó níláti kó ara rẹ̀ ni ìjánupẹlu ọ̀rọ̀ burúkú sísọ,kí ó má fi ẹnu rẹ̀ sọ̀rọ̀ ẹ̀tàn.
1.241617
Ɖe anyigbae ɖe adzɔ gbe ɖeka, eye ɖe woadzi dukɔa ɖe zi ɖeka?
Ǹjẹ́ a lè bí ilẹ̀ ní ọjọ́ kan,tabi kí á bí orílẹ̀-èdè kan ní ọjọ́ kan?
1.24123
Da gbe le ŋunye, elabena mewɔ nu vɔ̃ ɖe ŋuwò."
wò mí sàn, nítorí pé mo ti ṣẹ̀ sí ọ."
1.24116
elabena nɔvi atɔ̃ le asinye, bena wòaɖi ɖase na wo, bena woawo hã nagava fukpeƒe sia o.
Arakunrin marun-un ni mo ní; kí ó lọ kìlọ̀ fún wọn kí àwọn náà má baà wá sí ibi oró yìí.
1.240195
Wo dometɔ ɖe sia ɖe dona ɖe Mawu ŋkume le Zion.
títí tí ọ̀kọ̀ọ̀kan fi farahàn níwájú Ọlọ́run ní Sioni.
1.239426
Hekpe ɖe esia ŋu la, mianɔ fiazikpuiwo dzi adrɔ̃ ʋɔnu
ìwọ ti jókòó lórí ìtẹ́ rẹ, láti ṣe ìdájọ́ òdodo.
1.239389
Nye subɔlawo akpɔ dzidzɔ, ke miawo la, ŋu akpe mi.
Àwọn iranṣẹ mi yóo máa yọ̀,ṣugbọn ìtìjú yóo máa ba yín.
1.238965
Amesiame, si tso nyateƒe me la, ɖoa to nye gbe."
Gbogbo eniyan ti iṣe ti otitọ gbọ ohùn mi. "
1.237651
Eye nye fetu le nye Mawu gbɔ."
èrè mi sì ń bẹ pẹ̀lú Ọlọ́run mi."
1.237636
Eye womekpɔnɛ le agbagbeawo ƒe anyigba dzi o.
bẹ́ẹ̀ ni a kò le è rí i ní ilẹ̀ àwọn alààyè.
1.237312
Ke nye la mele egblɔm na mi bena: Migata nu kura o, eɖanye dziƒo o, elabena Mawu ƒe zikpui wònye;
Ṣugbọn èmi wá ń sọ fun yín pé, ẹ má ṣe búra rárá; ìbáà ṣe pé kí ẹ fi ọ̀run búra, nítorí ìtẹ́ Ọlọrun ni;
1.237204
Fia aɖeke mede enu le dukɔwo dome o; eye eƒe Mawu lɔ̃e, eye Mawu tsɔe ɖo fiae ɖe Israel blibo la nu.
Ati esan, laarin ọpọlọpọ awọn orilẹ-ède, kò si ọba iru si i, ati awọn ti o wà olufẹ Ọlọrun rẹ, Ọlọrun si gbé e ọba lori gbogbo Israeli.
1.237001
Domenyinu aɖeke mele Isai vi la gbɔ na mí o.
bẹ́ẹ̀ ni àwa kò ni ìní nínú ọmọ Jese!
1.236329
19 Ame kae nye ŋkuagbãtɔ, ɖe menye nye subɔlae oa,
19Ta ló fọ́jú bí kò ṣe ìránṣẹ́ mi,
1.235166
Mawu nye amenuvela alegbegbe.
jour reejueji be ktmwe to God.
1.235121
Abe alesi woŋlɔ ɖi ene bena: 'Nyagblɔla, siwo gblɔa ŋutifafanya kple nyanyuie la ƒe afɔwo nyo loo!'"
Gẹgẹ bi a ti kọ ọ pe: "Bawo ni awọn ẹsẹ ti awọn ti n waasu ihinrere ti alafia, awọn ti o mu awọn ayọ ohun rere wa!"
1.234931
eye wònye Vi wònye hafi, gake wòsrɔ̃ toɖoɖo le fu, siwo wokpe la me;
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé Ọmọ ni, ó kọ́ láti gbọ́ràn nípa ìyà tí ó jẹ.
1.234454
29 Esi wògblɔ esia la Yudatɔwo dzo eye nyahehe geɖe ɖo wo dome.
29 Nígbà tí ó ti sọ ọ̀rọ̀ wọ̀nyí fún wọn tan, àwọn Júù lọ, wọ́n bá ara wọn jiyàn púpọ̀."
1.233644
Míeɖe kuku, na anyigba mí ɖe mía fofo nɔviŋutsuwo dome."
Fun wa ni ilẹ-iní lãrin awọn arakunrin baba wa. "
1.233421
yonyeme la, woati miawo hã yome.
' Bí wọ́n bá ṣe inúnibíni mi, wọn yóo ṣe inúnibíni yín.
1.233306
Ame si be yeasee la, nesee,+ eye ame si be yeagbe la, negbe, elabena ƒome dzeaglãe wonye.
Ẹni tí ó bá fẹ́, kí ó gbọ́, ẹni tí ó bá fẹ́ kí ó má gbọ́, nítorí pé ìdílé ọlọ̀tẹ̀ ni ìdílé wọn.
1.233193
4 Nye ŋutɔ mayi Egipte kpli wò, eye nye ŋutɔ magakplɔ wò tso afi ma agbɔe, eye Yosef ƒe asie amia wò ŋkuwo."
4N óo bá ọ lọ sí Ijipti, n óo sì tún mú ọ pada wá, ọwọ́ Josẹfu ni o óo sì dákẹ́ sí."
1.232566
Tete Abram tso nuawo katã ƒe ewolia ne.
Abramu sì fún un ní ìdámẹ́wàá ohun gbogbo.
1.232353
Alea tututue wòanɔ na dzidzime vɔ̃ɖi siae.
Bẹ́ẹ̀ ni yóo rí fún ìran burúkú yìí.
1.232218
Eye viwòwo ƒe ŋutifafa asɔ gbɔ.
Ati nla ni yio je alafia awọn ọmọ rẹ.
1.232025
(Luka 13:12) Yesu da eƒe asi ɖe nyɔnua dzi, eye wòdzɔ enumake hede asi Mawu kafukafu me.
13 O si fi ọwọ́ rẹ̀ le e: lojukanna a si ti sọ ọ di titọ, o si nyìn Ọlọrun logo.
1.231862
Ƒle míawo kple míaƒe anyigbawo ɖe nuɖuɖu teƒe, eye míawo ŋutɔwo míazu kluviwo na Farao, eye míaƒe anyigbawo nazu etɔ.
Fi oúnjẹ ra àwa ati ilẹ̀ wa, a óo sì di ẹrú Farao.
1.231627
Eye Abram tsɔ nuawo katã ƒe ewolia nɛ.
Abramu sì fún un ní ìdámẹ́wàá ohun gbogbo.
1.231264
gblɔ bena: ʋɔnudrɔ̃laa ɖe nɔ dua ɖe me, amesi mevɔ̃a Mawu o, eye mesia ame hã o.
Ó ní, "Adájọ́ kan wà ní ìlú kan tí kò bẹ̀rù Ọlọrun, tí kò sì ka ẹnikẹ́ni sí.
1.231082
Eya ta ebia Laban be: "Nu kae nye esi nèwɔ ɖe ŋunye?
Ó sì wí fún Labani pé, "Èwo ni ìwọ ṣe sí mi yìí?
1.230662
nuxaxa geɖe ava anyigba sia dzi eye Mawu ƒe dɔmedzoe ava dukɔ sia dzi.
Fun nibẹ ni yio je ipọnju pipọ awọn ilẹ ati ibinu nla sori awọn enia yi.
1.230396
Mina míatsɔ akpedada ado ɖe eƒe ŋku me, eye míatsɔ kafukafuhawo atso aseye ɖe eŋu.
Ẹ jẹ́ kí á wá siwaju rẹ̀ pẹlu ọpẹ́;ẹ jẹ́ kí á fi orin ìyìn hó ìhó ayọ̀ sí i.
1.230067
Ɖe menye kesinɔtɔwo sẽa ŋuta le mia ŋuti, eye menye woawoe hea mi yia ʋɔnudrɔ̃ƒewo o mahã?
Awọn ọlọrọ̀ kò ha npọ́n nyin loju, nwọn kò ha si nwọ́ nyin lọ si ile ẹjọ?
1.229953
ke boŋ abe alesi amesi yɔ mi vɛ la le kɔkɔe ene la, nenema ke miawo hã minɔ kɔkɔe le miaƒe anyinɔnɔ katã me;
Ṣugbọn gẹ́gẹ́ bí ẹni tí ó pè yín ti jẹ́ mímọ́, bẹ́ẹ̀ ni kí ẹ̀yin náà jẹ́ mímọ́ ninu gbogbo ìwà yín.
1.229841
Fofowò hã ɖu nu, eye wono nu, ke edrɔ̃ ʋɔnu ɖe eteƒe, eye wòwɔ nu dzɔdzɔe, eye eme nyo nɛ.
Ṣe baba rẹ ko jẹ ati mu, ati sise pẹlu idajọ ati ododo, ki o le dara fun u?
1.229838
(Marko 8:34) Míegbea nu le mía ɖokui gbɔ nenye be míekpɔ egbɔ be míena mía ŋutɔwo míaƒe nudidiwo alo taɖodzinuwo xe mɔ ɖe míaƒe toɖoɖo Mawu bliboe nu o.
(Máàkù 8:34) Bá a bá sẹ́ níní ara wa, ohun tó túmọ̀ sí ni pé a kò jẹ́ kí àwọn ohun tá a fẹ́ kọ́wọ́ wa tẹ̀ àtàwọn ohun tá a nífẹ̀ẹ́ sí dí wa lọ́wọ́ tí a kò fi ní lè ṣègbọràn sí Ọlọ́run délẹ̀délẹ̀.
1.22938
"bene wòanyo na wò, eye nana agbe didie le anyigba dzi!"
"Kí ó lè dára fún ọ, ati kí o lè pẹ́ lórí ilẹ̀ náà.
1.229136
Mi Yakob ƒe dzidzimeviwo katã, mitsɔ ŋutikɔkɔe nɛ!
Gbogbo ẹ̀yin ìran Jakọbu, ẹ fi ògo fún un!
1.228976
5 Nenema kee wònɔ le Lot ƒe ŋkekea me.
Bákan náà ni ó rí ní àkókò ti Lọti.
1.228348
Elabena nyagblɔɖilawo kple nunɔlawo siaa tsa tsaglãla yi anyigba si womenya o la dzi.'"
Nítorí àwọn wolii ati àwọn alufaa ń lọ káàkiri gbogbo ilẹ̀ náà,wọn kò sì mọ ohun tí wọn ń ṣe.
1.228232
Wo kple wo tɔgbuiwo da vo ɖe ŋunye va se ɖe egbeŋkeke sia dzi.
Àwọn ati àwọn baba ńlá wọn ṣì tún ń bá mi ṣọ̀tẹ̀ títí di òní olónìí.
1.227968
Eye ame siwo léa fui la nasi le eŋkume.
Kí àwọn tí ó kórìíra rẹ̀ sá níwájú rẹ̀.
1.227525
2 Eya ta dukɔ la va Betel, eye wobɔbɔ nɔ afi ma le Mawu vavã la ŋkume va se ɖe fiẽ, eye wodo ɣli hefa avi sesĩe.
Àwọn eniyan bá wá sí Bẹtẹli, wọ́n jókòó níwájú Ọlọrun títí di ìrọ̀lẹ́, wọ́n sì sọkún gidigidi.
1.227248
Ke miɖoe ɖa le ŋutifafa me boŋ, bene wòava gbɔnye, elabena mele eya kple nɔviawo lalam.
Ṣùgbọ́n ẹ sín ín jáde lọ́nà àjò ni àlàáfíà, kí òun lè tọ̀ mí wá; nítorí tí èmí ń fi ojú sí ọ̀nà fún wíwá rẹ̀ pẹ̀lú àwọn arákùnrin.
1.226665
"Ɣekaɣi gɔ̃ wòaku, ne eƒe ŋkɔ natsrɔ̃ ɖa?"
"Nígbà wo ni yóò kú, ti orúkọ rẹ̀ yóò sì run?"
1.226608
Le esiawo megbe la Mawu na ʋɔnudrɔ̃lawo ɖu dukɔa dzi va se ɖe nyagblɔɖila Samuel dzi.
"Lẹ́yìn èyí ó fún wọn ní àwọn onídàájọ́ títí di àkókò wolii Samuẹli.
1.226349
Fofowò hã ɖu nu, no nu, Gake edrɔ̃ ʋɔnu ɖe eteƒe hewɔ nu dzɔdzɔe.
Ṣe baba rẹ ko jẹ ati mu, ati sise pẹlu idajọ ati ododo, ki o le dara fun u?
1.226262
Eye dukɔ geɖewo asubɔ eya kple via kpakple eƒe tɔgbuiyɔvi, vaseɖe esime azã nade na eƒe anyigba, eye wòasubɔ dukɔ geɖewo kple fia gãwo.
Gbogbo orílẹ̀-èdè ni yóo máa ṣe ẹrú òun ati ọmọ rẹ̀, ati ọmọ ọmọ rẹ̀, títí àkókò tí ilẹ̀ òun pàápàá yóo fi tó, tí ọpọlọpọ orílẹ̀-èdè ati àwọn ọba ńláńlá yóo sì kó o lẹ́rú.
1.225904
Esiae nye ku evelia."
Èyí ni ikú keji."
1.225713
Se bubu aɖeke megali si lolo wu esiawo o."
Ko si si ofin miran, ti o tobi jù wọnyi lọ.
1.22571
Woatsɔ ame si da le sea dzi la aƒu gbe ɖe kpodzo bibi aɖe me.
ati pé ẹnikẹ́ni tí kò bá ṣe bẹ́ẹ̀, a óo sọ ọ́ sinu adágún iná tí ń jó.
1.225194
Ke miɖoe ɖa le ŋutifafa me boŋ, bene wòava gbɔnye, elabena mele eya kple nɔviawo lalam.
Ṣugbọn ẹ sìn i jade lọna-ajò li alafia, ki on ki o le tọ̀ mi wá: nitoriti emi nwò ọ̀na rẹ̀ pẹlu awọn arakunrin.
1.22498
Nenema kee ne womena amewo nya Mawu ƒe ŋkɔ Yehowa o ɖe, ɖe woa kple Mawu dome ate ŋu anɔ kplikplikplia?
Bákan náà, téèyàn ò bá mọ̀ pé Jèhófà ni orúkọ Ọlọ́run, báwo ló ṣe lè sún mọ́ ọn ní gidi?
1.224433
Gblɔ na Israel-viwo be, woatia sitsoƒedu, siwo ŋu meƒo nu le na mi to Mose dzi la;
"Sọ fún àwọn ọmọ Israẹli pé kí wọ́n yan àwọn ìlú ààbò tí mo bá Mose sọ nípa rẹ̀, pé kí ó sọ fun yín.
1.223912
Azɔ Afetɔ gblẽ mí ɖi, eye wòtsɔ mí de asi na Midian."
' Ṣugbọn nisinsinyii OLUWA ti kọ̀ wá sílẹ̀, ó sì ti fi wá lé àwọn ará Midiani lọ́wọ́.
1.223835
esime ŋukeɣletiviwo katã le aseye tsom, eye Mawu ƒe viwo katã gli kple dzidzɔa?
tí àwọn ìràwọ̀ òwúrọ̀ ń jùmọ̀ kọrin,tí gbogbo àwọn ọmọ Ọlọrun sì búsáyọ̀?
1.223405
Alo ɖe nèɖu ati, si ŋuti meɖe se na wò be, megaɖu eƒe ɖeke o la ƒe ɖe mahã?
Ṣé ìwọ ti jẹ nínú èso igi tí mo pàṣẹ fún ọ pé ìwọ kò gbọdọ̀ jẹ nínú rẹ̀ ni?" _ Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB) _ Download The Bible App Now
1.222068
Eye wògblɔ na wo bena: Esɔ gbɔ.
Ó sì wí fún wọn pé, "Ó tó."
1.221928
edzi na wò nyuie eye nànɔ agbe didi le anyigba dzi."
"Kí ó lè dára fún ọ, ati kí o lè pẹ́ lórí ilẹ̀ náà.
1.2219
Amesi tso Mawu me la, sea Mawu ƒe nyawo; miawo la miele wo sem o, le esi mietso Mawu me o la ta." - Yohanes 8:46, 47.
47 Ẹniti iṣe ti Ọlọrun, a ma gbọ́ ọ̀rọ Ọlọrun: nitori eyi li ẹnyin kò ṣe gbọ, nitori ẹnyin kì iṣe ti Ọlọrun.
1.221892
2 "Azɔ menyae be àte ŋu awɔ nu sia nu
2"Èmi mọ̀ pé, ìwọ lè e ṣe ohun gbogbo,
1.221751
Eye eya ŋutɔe tsɔ eƒe asiwo wɔ anyigba ƒuƒui la.
àti ọwọ́ rẹ̀ ni ó fi dá ìyàngbẹ ilẹ̀.
1.221653
Nu ka tae nèɣla ɖokuiwò le xaxaɣiwo?
Èéha ti ṣe, tí ìwọ fi ara rẹ pamọ́ ní ìgbà ìpọ́njú?
1.221432
11 Ale ame siwo katã le dugbo la nu kple ametsitsiawo gblɔ be: "Míawoe nye ɖasefowo!
11 Gbogbo awọn enia ti o wà li ẹnu-bode, ati awọn àgbagba, si wipe, Awa ṣe ẹlẹri.
1.221211
Míenɔa amehawo dome yia Mawu ƒe aƒe la me.
Dipo, ti o ba wa ilu lãrin awọn enia mimọ ninu awọn ará ile Ọlọrun,
1.220937
Womeɖo ŋku wò amenuveve geɖeawo dzi o,
Nwọn kò ranti ọpọlọpọ ãnu rẹ.
1.220847
Ekema nu ka tae wò dɔla agazu agba na nye aƒetɔ fia la?
Éṣe tí ìránṣẹ́ rẹ yóò fi di ẹrù ìnira fún olúwa mi ọba?
1.220704
gbɔgbɔ vɔ̃ siawo ƒomevi o negbe ɖe miado gbe ɖa, atsi nu dɔ ko hafi."
29 O si wi fun wọn pe, Irú yi kò le ti ipa ohun kan jade, bikoṣe nipa adura ati àwẹ.
1.220567
nya me na Mawu." 12 Nyateƒe ame sia ame ana akɔnta tso eɖokui ŋu na Mawu.
12 Njẹ nitorina, olukuluku wa ni yio jihin ara rẹ̀ fun Ọlọrun.
1.220314
Eya ta ɖi nãyi ɖakpe wo, eye nãdze wo yome ayi kpli wo elabena nyee dɔ wo ɖo ɖe gbɔwò.
Dìde, lọ sí ìsàlẹ̀, kí o bá wọn lọ láì kọminú nítorí èmi ni mo rán wọn.
1.2202
Oo Israel, maɖi ɖase ɖe ŋuwò.
Gbọ, Israeli, emi o si jẹri fun ọ.
1.220196
23 Afetɔ wò Mawu atsɔ wo ade asi na wò, eye nàsi wo va se ɖe esime wotsrɔ̃ vɔ.
23 Ṣugbọn OLUWA Ọlọrun rẹ yio fi wọn lé ọ lọwọ, yio si fi iparun nla pa wọn run, titi nwọn o fi run.
1.220124
Nyateƒee, anyrawɔwɔ gblẽ nu le ameƒomea ŋu ƒe akpe geɖe.
Ọlọrun ti fi sùúrù farada awọn eniyan buburu fun ẹgbẹẹgbẹrun ọdun.
1.219838
Tadedeagu Vavãtɔ Naa Amewo Wɔa Ðeka
Ẹ̀sìn tòótọ́ ń mú kí àwọn èèyàn wà níṣọ̀kan
1.21975
Ðeko mègana vinye la nagbugbɔ ayi afi ma o."
Má ṣe mú ọmọ mi padà sí ibí yẹn. "
1.21929
6 Eya ta, azɔ la mibɔbɔ mia ɖokuiwo ɖe Mawu ƒe asi sesẽ la te, be ne ɣeyiɣi
6 Nitorina ẹ rẹ̀ ara nyin silẹ labẹ ọwọ́ agbara Ọlọrun, ki on ki o le gbé nyin ga li akokò.
1.219237
Eye woalé nye ŋkuɖodzinya siwo mafia wo la me ɖe asi la,
àti ẹ̀rí mi tí èmi yóò kọ́ wọn,
1.219192
17 Afi sia wokpee le hesubɔe, ke wo dometɔ aɖewo meka ɖe edzi be Yesu ŋutɔe nye ema o.
17 Nigbati nwọn si ri i, nwọn foribalẹ fun u: ṣugbọn awọn miran ṣiyemeji.
1.219103
Egblɔ be: "Mia Fofo la nya nu siwo le mia hiãm hafi mieva bianɛ gɔ̃ hã."
Ó tún wá fi wọ́n lọ́kàn balẹ̀ pé: "Baba yín mọ àwọn ohun tí ẹ ṣe aláìní kí ẹ tó béèrè lọ́wọ́ rẹ̀ rárá."
1.218877
17 Afetɔ gagblɔ na Mose be: "Mawɔ nya sia si gblɔm nèle la hã dzi, elabena meve nuwò, eye menya wò kple wò ŋkɔ."
17 OLUWA si wi fun Mose pe, Emi o ṣe ohun yi ti iwọ sọ pẹlu: nitoriti iwọ ri ore-ọfẹ li oju mi, emi si mọ̀ ọ li orukọ.
1.218645
Míeɖe kuku, na anyigba mí ɖe mía fofo nɔviŋutsuwo dome."
Fún wa ní ilẹ̀ ìní láàrín àwọn arákùnrin baba wa."
1.217693
Ame si wɔ nu gãwo le Egipte,
ẹni tí ó ti ṣe ohun ńlá ní Ejibiti,
1.217454
Nenema ke Amegbetɔvi la hã le fu kpe ge atso wo si mee.
Bẹ́ẹ̀ náà ni Ọmọ-Eniyan yóo sì jìyà lọ́wọ́ wọn.
End of preview. Expand in Data Studio

Ewe-Yoruba_Sentence-Pairs Dataset

This dataset contains sentence pairs for African languages along with similarity scores. It can be used for machine translation, sentence alignment, or other natural language processing tasks.

This dataset is based on the NLLBv1 dataset, published on OPUS under an open-source initiative led by META. You can find more information here: OPUS - NLLB-v1

Metadata

  • File Name: Ewe-Yoruba_Sentence-Pairs
  • Number of Rows: 167046
  • Number of Columns: 3
  • Columns: score, Ewe, Yoruba

Dataset Description

The dataset contains sentence pairs in African languages with an associated similarity score. Each row consists of three columns:

  1. score: The similarity score between the two sentences (range from 0 to 1).
  2. Ewe: The first sentence in the pair (language 1).
  3. Yoruba: The second sentence in the pair (language 2).

This dataset is intended for use in training and evaluating machine learning models for tasks like translation, sentence similarity, and cross-lingual transfer learning.

References

Below are papers related to how the data was collected and used in various multilingual and cross-lingual applications:

[1] Holger Schwenk and Matthijs Douze, Learning Joint Multilingual Sentence Representations with Neural Machine Translation, ACL workshop on Representation Learning for NLP, 2017

[2] Holger Schwenk and Xian Li, A Corpus for Multilingual Document Classification in Eight Languages, LREC, pages 3548-3551, 2018.

[3] Holger Schwenk, Filtering and Mining Parallel Data in a Joint Multilingual Space ACL, July 2018

[4] Alexis Conneau, Guillaume Lample, Ruty Rinott, Adina Williams, Samuel R. Bowman, Holger Schwenk and Veselin Stoyanov, XNLI: Cross-lingual Sentence Understanding through Inference, EMNLP, 2018.

[5] Mikel Artetxe and Holger Schwenk, Margin-based Parallel Corpus Mining with Multilingual Sentence Embeddings arXiv, Nov 3 2018.

[6] Mikel Artetxe and Holger Schwenk, Massively Multilingual Sentence Embeddings for Zero-Shot Cross-Lingual Transfer and Beyond arXiv, Dec 26 2018.

[7] Holger Schwenk, Vishrav Chaudhary, Shuo Sun, Hongyu Gong and Paco Guzman, WikiMatrix: Mining 135M Parallel Sentences in 1620 Language Pairs from Wikipedia arXiv, July 11 2019.

[8] Holger Schwenk, Guillaume Wenzek, Sergey Edunov, Edouard Grave and Armand Joulin CCMatrix: Mining Billions of High-Quality Parallel Sentences on the WEB

[9] Paul-Ambroise Duquenne, Hongyu Gong, Holger Schwenk, Multimodal and Multilingual Embeddings for Large-Scale Speech Mining, NeurIPS 2021, pages 15748-15761.

[10] Kevin Heffernan, Onur Celebi, and Holger Schwenk, Bitext Mining Using Distilled Sentence Representations for Low-Resource Languages

Downloads last month
15

Collection including michsethowusu/ewe-yoruba_sentence-pairs